Emeritus Ayo Bamgbose: Ibánújẹ́ ni ojú yẹpẹrẹ tí ìjọba fi n wo olùkọ́ báyìí jẹ́ fún mi
Odún 1952 ni mo kọ́kọ́ mu Bíà rí, ṣùgbọ́n ẹnu mi kò kán Bíà mọ̀ lẹ́yìn ti mo fẹ́ bi ṣelẹṣe- Ayo Bamgbose
Iriri kọja ẹgbẹ abẹwu, béé ohun ti oju agba ri to fi jin sinu kuro ni kekere.
Nitori pe BBC Yoruba fẹ́ ki awọn ọ̀dọ́ asiko yii kọ ẹkọ lara awọn agbaagba to ti wé odò aṣeyọri ja lénu iṣẹ ti wọn yan laayo ni a ṣe bẹrẹ abala iriri agba yii.
BBC fẹ ki ọdọ kọ ẹkọ lara awọn agbalagba ti oju wọn ti ri to yii ni ki aye le tun fi roju pada ki nkan le yipada si rere pelu iwa omoluwabi awon ọdọ asiko yii.
- Àwọn Olùkọ́ Akure pegedé lórí ètò Akomolede àti Aṣa lórí BBC Yorùbá
- Egungun Oloolu ti ilẹ̀ Ibadan fojú han aráyé! Gbọ́ àwọn ǹkan tó ń dẹ́rù ba obìnrin, ọmọde nípa rẹ̀ àti èèwọ̀ rẹ̀
- Wo ọ̀nà àrà àti ẹ̀fẹ̀ tí Yorùbá fi ń polówó ọ̀jà láyé àtijọ́ àti òde òní
- Agbọ́nmágbọ́ntán, Agọ̀mágọ̀jù, mọ̀ síi nípa àwọn orúkọ Ìjàpá nínú alọ àpagbè Yorùbá
- Báyìí ni Egúngún àti Orò ṣe jọ bí Ẹ̀ṣà Egúngún nílẹ̀ Yorùba
- Àwọn aya Yekeen Ajileye ló fa ìpinyà láàrin wa débi pé mo fẹ́ pa ara mi - Abija

Ta ni Ojogbon Ayo Bamgbose?
A bi Ayo Bamgbose ni ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu kinni, ọdun 1932 si idile Alufaa Sangodipe Bamgbose ni Odopotu.
Egungun ati Sango ni wọn n bọ nile wọn ni eyi to hande ninu oruko re Ba - mi- gb-e ose Sango.
O lo sile ẹkọ St Anfrews College nibi to ti di akọṣẹmọṣẹ oluko ni ọdun 1951.
Lẹyin naa lo wa si Fasiti akọkọ ni Naijiria to wa ni ilu Ibadan nipinlẹ Oyo nibi ti sanmọnti ti gbe dun ilẹ to tun ni ọgba eranko.Títí di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yìí, èmi gan an kò mọ irú ẹni tí Wole Soyinka jẹ́- Ojọ̀gbọ́n Wole Soyinka
Eko nipa ede oyinbo lo kọkọ kọ ni Fasiti Ibadan ko to lọ mọ sii nipa imọ ẹda ede ni University of Edinburg nibi to ti gba oye ọmọwe lọdun 1963.
- Kí lo mọ̀ nípa ìgbeyàwó Àbẹ̀ẹ́lẹ̀, Àṣàǹte, Ọkọ Káalẹ́ àti Gbàmí o ràmí?
- Pius Adesanmi ní kò bá rọ́pò Wole Soyinka tí kò bá kú - ọmọ Naijiríà
- Wo àwọn nọ́mbà ìpè agbófinró tó yẹ kò mọ̀, èyí tó pè tí ìkọlù agbébọn bá dé
- Òṣèré tíátà, ẹ má jẹ́ kí àbùkù wọ ìlàkàkà yín láti kó ọrọ̀ jọ - Ajirebi
- 'Láti ojú orun, ohùn kan máa ń tọ́ka ewé àti ègbòogi sí mi, báyìí la ṣe ń ṣe agbo fún ǹkan ọmọ ọkùnrin'
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- U.S. yóò máa fún àwọn ọmo Nàìjíríà kan ní físà ìwé ìrìnnà láì ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò

Oríṣun àwòrán, @Bamgbose
Lati igba naa lo ti n sise olukoni ni Fasiti Ibadan to si ti kọwe pupọ nipa imọ ẹda ede ati idagbasoke ede Yoruba ni pato.
Bamgbose ni akọṣẹmọṣẹ imọ ẹda ede akọkọ nilẹ Adulawo to di ọmọ ẹgbẹ Linguistic Society of America. LSA.
Oun ni Adulawo akọkọ to jẹ aarẹ International Association of World Englishes.
- Wo ohun tó yẹ ko mọ̀ nípa àrùn pọ̀jẹ̀-pọ̀jẹ̀ Marburg tó ń yára ṣekú pani
- Mo kọ ìwà ẹlẹ́yàmẹ́yà ló jẹ́ kí ń má a kọ ọmọ Abraka, Ebonyi, Plateau àti Benue nílé ẹ̀kọ́ mi lọ́fẹ̀ẹ́- Oba Abolarin
- Ọlọ́run fi ẹ̀mí Sunday Igboho ta gbogbo àwa tókù jí ni, ọ̀rọ̀ yìí ti kọjá ìsòpọ̀ Nàìjíríà - Oba Gbolahan Shomolu
- Baba Latin ṣe bẹbẹ lórí ètò Sé o láya?, sùgbọ́n...
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ́ Aláàfin, ẹni tó pààrọ̀ nǹkan obìnrin sí ti ọkùnrin
- Ǹkan tí àwon omo Naijiria ń so nípa ''delegates'' tó ń dìbò fún egbé òsèlú ní yìí...
- Exclusive: Atiku dára ju Buhari ní ìlọ́po méjì - Obasanjo #BBCNigeria2019
Oun nikan ni won fun ni Nigerian National Order of Merit lodun 1990 yato si ọpọlọpọ oye akada ati awujọ miran.
Bayii, Emeritus Ayo Bamgbose ti kọja aadọrun ọdun lori oke eepe.
Opo Ojogbon to ti lamilaaka ni wọn ti mu ninu omi ọgbọn Baba Bamgbose.

Kini Ojogbon yii tun só nipa iriri re ki ọdọ tun fi kọgbọn?
Ojogbon Agba, Ayo Bamgbose sọrọ nipa iriri rẹ̀ nigba to kọkọ mu ọti bíà ri laye.
Iriri yii buru to bẹẹ ti o bì titi ilẹ fi mọ ni ọjọ keji ni.
Baba ni lati igba naa ni won ko ti fẹnu kan ọti lile mọ, eyi fihan pe agba wa bura, bi èwe ko ba ṣe ẹ ri ni ọrọ iriri.
Ni afikun, O sọrọ nipa ipo oluko ni atijo ati ni isiyi to n bani lokan jẹ gidi.
- Wo ipa mánigbàgbé táwọn ààrẹ ní sáà ìjọba alágbádá kẹ́rin ṣe
- Báwo ni ìlù gángan se bẹ̀rẹ̀?
- Irọ́ ni o! Èmi kò forí ṣọta ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú kankan - Obasanjo
- Buhari o, tètè ṣètò àtúntò Nàíjíríà ká le è dènà ogun abẹ́lé lẹ́ẹ̀kejì - Obasanjo figbe bọnu
- Wo ohun tí o kò mọ̀ nípa Morenikeji Lasisi, olórí ẹrú tó ti bá Aláàfin mẹ́ta ṣiṣẹ́