Oba Gbolahan Timson Shomolu Bariga ní 'Restructuring' ti bọ́ aṣọ kò bá Omọyẹ mọ́!
Èpè Lisabi ló ja Awolowo, Abiola tó tun ń ja ìran Yorùbá báyìí- Oba Shomolu
Oba Gbolahan Timson, Jagunmolu 11 ti ilu Shomolu Bariga ni ipinle Eko sọrọ ilẹ kun lori ohun to n ṣẹlẹ bayii ni Naijiria.

Kabiesi ni oun ati idile rẹ faramọ Sunday Igboho ati gbogbo awọn ajijangbara to fẹ ki iran Yoruba gba ominira lasiko yii.
O ni: O ti pẹ ti a ti n pariwo pe ki ẹya kọọkan maa mojuto ọrọ aje wọn ṣugbọn ti ijọba apapọ ko gbọ́.
- Ẹ̀yin òṣìṣẹ́ ìjọba, dẹndẹ ìyà yóò jẹ orí yín bí Nàìjíríà bá pínyà pẹ́rẹ́, toríi Yoruba Nation! - Oluwo
- 'Kò sí ààtò fún òfin Sharia àti ẹtọ àwa ẹlẹsìn Islam nínú Oduduwa Republic, a ò gbà!'
- Ilẹ̀ Yorùbá kìí ṣe ibi kátàkárà fún yín, ẹ̀yin àgbà tẹ ń gbárùkù ti ọ̀dọ́ lẹ́yìn láti máa da ìlú rú ẹ sọ́ra - Ẹgbẹ́ YWG
- Kí ni Nàìjíríà ti jèrè lára gbogbo ààrẹ tó ti jẹ látọdún 1999? BBC tú àlàyé síta
- Ẹ̀mí àìrí lé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde ni ilé ẹ̀kọ́ St Claire's ní Offa
- Ọwọ́ EFCC tẹ ọmọ Yahoo tó fẹ́ ra ọkọ̀ SUV tí iye rẹ̀ tó 44 mílíọ́nù pẹ̀lú Bitcoin
- A ti rí ọmọ ilé kéú 11 míì nínú àwón tí agbébọn jí gbé ní ìpínlẹ̀ Niger
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà ti kéde pé IPOB àti ESN ló pa Gulak tó kú lánàá
- Àwon ẹlẹ́ja ṣe ìfẹ̀hónúhàn nílùú Akure nítorí ọ̀kan nínú wọn tí ilé wó pa
Oba Shomolu ni pe ko buru ti onikaluku ba pin gaari ti koowa n ṣe ọrọ aje rẹ bi o ṣe wu u to si n mojuto iṣoro eeyan rẹ.
O ni: 'Restructuring'ti 'late', aṣọ ko ba Omoye mọ, Omọyẹ ti rin ihoho wọ ọja.
Bakan naa ni Kabiesi sọrọ lori itan Lisabi Agbongbo Akala ati epe to n ja iran Yoruba.

O mẹnuba ẹkọ to yẹ ki itan ogun Egba kọ gbogbo iran Yoruba ati ọna abayọ lasiko yii nitori pe ẹni to kan lo mọ ni iṣoro eto aabo ja si bayii.
- Wo ìdí tí ECOWAS fi dá Mali dúró, tó tún fún àwọn ológun ní gbèdéke láti gbé ìjọba sílẹ̀
- Ọ̀pọ̀ ọ̀rẹ́ àti aya lọ lẹ́yìn ti ojú mi lọ ní 2012 ṣùgbọ́n lónìí iṣẹ́ Àdìrẹ ti sọ mi dí eèyàn- Muritala David
- Omoyele Sowore dèrò ilé ìwòsàn lẹ́yìn tó fara gba ọta gáàsì tajútajú l'Abuja
- Ẹ kó àwọn ọmọ ọdún 12 títí dé 15 wá fún abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19
Ni ipari Oba Gbolahan Timson ni ki iran Yoruba dide giri lasiko yii ki.

