Democracy day 2021: Kí ni Nàìjíríà ti jèrè lára gbogbo ààrẹ tó ti jẹ látọdún 1999?

Àkọlé fídíò, Democracy day 2021: Kí ni Nàìjíríà ti jèrè lára gbogbo ààrẹ tó ti jẹ látọdún 1999?

Ọdun 1960 ni orilẹede Naijiria gba ominira lọjọ kinni oṣu kẹwaa.

Sibẹsibẹ ọdun mẹtala gbako ni Naijiria lo loko ẹru ijọba ologun.

Fun ẹkunrẹrẹ iroyin lorii bi awọn ologun ditẹ gbajọba ninu eyi ti wọn ti ṣekupa Tafawa Balewa at'awọn olori ijoba mii bii Samuel Ladoke Akintola to jẹ olori ijoba ilẹ Yoruba nigba naa"

Awọn olori orilẹede Naijiria

Bi Shehu Shagari ṣe di aarẹ apaṣẹ-waa akọkọ lorileede Naijiria.

Titi titi ti Aarẹ Buhari to wa lori alefa bayii ṣe gba eku ida lọwọ aarẹ ana, GoodLuck Jonathan, fidio Laa Han Mi BBC Yoruba ge akanṣe alaye yii jade.