Covid-19 Vaccine: Ẹ kó àwọn ọmọ ọdún 12 sí 15 wá fún abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19

Oríṣun àwòrán, @Reuters
Ajọ isọkan agbaye EU ti fọwọ si i pe awọn ọmọ ọdun mejila si mẹẹdogun naa le wa gba abẹrẹ Covid-19.
Wọn ni awọn ọdọ langba gba abẹrẹ naa gba abẹrẹ naa ko si si ipalara kankan nitorinaa, awọn ọmọde lee gba a.
"Igbesẹ naa yoo mu igbega ba eto ifunilabẹrẹ ajẹsara pẹlu bi orilẹede Germany ṣe ni awọn ti fẹ bẹ́rẹ si ni fun awọn ọmọ to ti le ni ọdun mejila lati inu oṣu to n bọ.
- Ọkọ àti ìyàwó ri ọmọ ọdún kan àbọ mọlẹ láàyè lọgànjọ oru, àṣírí tú!
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà ti kéde pé IPOB àti ESN ló pa Gulak tó kú lánàá
- Wo àsìkò tí ìdíje "BBNaija lockdown reunion" yóò bẹ̀rẹ̀
- Àwọn jàndùkú agbébọn yìnbọn pa ọkùnrin oníṣòwò kan nílùú Ibadan
- Ọwọ́ EFCC tẹ ọmọ Yahoo tó fẹ́ ra ọkọ̀ SUV tí iye rẹ̀ tó 44 mílíọ́nù pẹ̀lú Bitcoin
- Omoyele Sowore dèrò ilé ìwòsàn lẹ́yìn tó fara gba ọta gáàsì tajútajú l'Abuja
Nilẹ Amẹrika ati Canada, wọn ti fi aṣẹ si ki awọn ọdọ langba gba abẹrẹ naa.
Kọmisọna eto ilera fun ajọ EU, Stella Kyriakides kan sara si igbesẹ naa pe o jẹ iṣisẹ kan lati sunmọ opin ajakalẹ arun Covid-19 amọ o ni awọn eeyan ni yoo yan boya wọn fẹ ki awọn ọmọ wọn gba a tabi ki wọn ma gba.
"Tayọ ipinu ijọba, ipinu obi sọọ nika ni eleyi fun awọn ọmọ wọn," o kọ ọ si ori Twitter.
Ẹwẹ, gẹgẹ bi ajọ oju lalakan fi n ṣọ ori, wọn ni awọn ti ṣ aridaju ti awọn si fi n da gbogbo ilu loju pe ko si ewu ninu rẹ bi awọn ọmọde ba gba a.
- Ọjọ́ kínní oṣù kẹfà ni Amotekun yóò bẹ̀rẹ̀ sí ni máa gbógun tàwọn ọ̀daràn àti ajínigbé nílẹ̀ Yorùbá
- Wo ìdí tí ECOWAS fi dá Mali dúró, tó tún fún àwọn ológun ní gbèdéke láti gbé ìjọba sílẹ̀
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà ti kéde pé IPOB àti ESN ló pa Gulak tó kú lánàá
- Wo àsìkò tí ìdíje "BBNaija lockdown reunion" yóò bẹ̀rẹ̀











