Pius Adesanmi: Awọn ọmọ Nàìjíríà ń ṣelédè lẹ́yìn akọni tó lọ

Adesanmi

Oríṣun àwòrán, Adesanmi

Àkọlé àwòrán, Pius Adesanmi: Awọn ọmọ Nàìjíríà ń ṣelédè lẹ́yìn akọni
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Gbógbo ọmọ Nàìjíríà nílé àti lẹ̀yìn odi tó jẹ́ ọ̀rẹ́ àti alábaṣiṣẹ́pọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n Pius Adebola Adesanmi tó jẹ́ Ọlọ́run nípe, lásìkò ti bàálù boeing 737 X8 tó ń lọ si Narobi lọ́jọ́ àikú, ọjọ Kẹ́wàá oṣù Kẹ́ta ọdun 2019 já, lẹ̀yìn ìṣẹ́jú mẹ́fà to gbera.

Gbogbo àwọn tó sọ̀rọ̀ nípa ọ̀jọ̀gbọ́n Adesanmi pẹlu BBC Yoruba sàlàyé pé, oloogbe naa jẹ ẹni ti a n pe ni olùfẹ ọmọ ènìyàn, ẹni to fẹ́ràn ará ìlú ti kìí fi ti ẹya ṣe.

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Pius Adesanmi ní Wole Soyinka ìran yìí - ọmọ Naijiríà

Wọn ní akikanju ẹdá ni ọjọgbọ́n Adesanmi, ẹni to ṣetan láti jàjà ominira fun ilẹ adúlawọ nípa kíkọ ìwe ati ṣise ìlanilọye fun àwọn ọdọ.

Wọn fi kun pé, ohun ti Nàìjíríà sọnu nípa ẹni to ku yìí kii ṣe ńkan to ṣe fẹnu sọ tan.

Àkọlé fídíò, Seyi Makinde: Màá fẹ́ káwọn aráàlú mọ ìpa ìjọba mi lára sí rere

Ní àgbo àwọn ọmọwe, wọn ni ọjọgbọn Adesanmi ni wọn woye pé yóò ropò ọjọgbọ́n Wole Soyinka, nígbà ti wọn ba lọ ibi àgbà ń rè.

Àkọlé fídíò, #Governorship Election: Òjò ni wá, a kò bẹ́nì kan ṣọ̀tá -Sanwo Olu

Bakan náà ni àwọn ènìyàn lóri ayálujara náá ń banujẹ lóri akoni naa, to fi mọ Oby Ezekwesili.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3