Gbajugbaja oṣere tiata, Bolaji Amusan fi hàn wá bó se láyà to lori ètò ṣé o láyà?
Ori eto ṣe o laya ti BBC News Yoruba lo ti dahun awọ̀n ibeere to jẹ mọ̀ asa, iṣesi ati owe Yoruba.
- Yemi Elesho tún fi ẹnu já nǹkan níléeṣẹ́ BBC
- Ìdí rè é tí a ó fi gùnlẹ̀ ìyanṣẹ́lódí aláìlójọ́ káàkiri Naijiria - Ẹgbẹ́ Dokítà
- Èyí ni àlàyé lórí ètò ìsìnkú Tope AjogbaJesu àti ọjọ́ tí wọn yóò sin ín
- Ọ̀gá Àgbà Ọlọ́pàá, ẹ ríi dájú pé ẹ tú gbogbo àṣírí nípa ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan Abba Kyari àti Hushpuppi - Àpapọ̀ Agbẹjọ́rọ̀
- Ọ̀pẹ́lọ̀pẹ́ Olorì Ladun aya Ooni Sijuwade ni mo fi gba òmìnira tí mo sì dúpẹ́ lọ́wọ́ Olorun- Abobaku Ooni Sijuwade
Lẹ́yin o rẹyin ọ̀gbẹ́ni Amusan gbà pé, o di dandan ki òun ló tún ẹ̀kọ Yoruba kọ nítọri pe imọ oun kù díẹ̀ káàto nínú àwọn ibéèrè ti a bii

