Okunade Sijuwade: Ìfẹ́ tí Sarun tó súnmọ́ Ooni jù láyé ní sí í ló sọ ọ́ di abọ́bakú- Adeyeye Adesiyan Lowa Adimula
Ká ni mi ò tíi di Oloye kí ooni Sijuwade Okunade Olubuse to ku ni.....Lowa Adimula ti Ile Ife
Lowa Adimula, Oba Adeyeye Adekola Adesiyan ni abobaku Oba Ooni Sijuwade Okunade Olubuse keji ti wọn bi lodun 1930 to waja lodun 2015.
Oba Sijuwade ni Lowa Adimula jẹ oye Abobaku fun lati ibẹrẹ ni eyi ti wọn jọ n jẹ, ti wọn jọ n mu koda, Lowa ni ko si nkan ti wọn ki jọ ṣe nitori pe abobaku lo sunmọ Oba julọ.
- Bí ọkọ mi ṣe fi ẹ̀wọ̀n irin dè mí mọ́ bẹ́ẹ̀dí tó fipà bá mi lòpọ̀ títí oyún fi bàjẹ́ lára mi'
- 'Restructuring' la fi ta Buhari fún ìran Yorùbá, ṣùgbọ́n ó dùn mi pé irọ́ ni Buhari pa- Olagunsoye Oyinlola
- Títí di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yìí, èmi gan an kò mọ irú ẹni tí Wole Soyinka jẹ́- Ojọ̀gbọ́n Wole Soyinka
- Aya Aarẹ Ghana ati aya ìgbákejì Aarẹ Ghana ti dá gbogbo owó oṣù tí wọ́n gbà láti 2017 padà sápò ìjọba
- Ọkùnrin márùn-ún tí wọ́n bá lórí kerewà bọ́ sọ́wọ́ Ọlọ́pàá ẹ̀sìn Islam
- Ó kéré tán, ajínigbé ti pa èèyàn 222 láàrìn oṣù mẹ́ta ní Kaduna- Gomina El Rufai
- Ìdí tí mo fi jú ọmọ mi ọmọ ọdún méjì látorí ilé gogoro sílẹ̀
- Cubana Chief Priest ra màálù 46 fún ìsìnkú ìyá ọ̀gá rẹ̀, àwọn ọmọ Naijiria ń fi èrò wọn hàn

Oba Adeyeye ṣalaye iru eeyan ti Oba Okunade Sijuwade jẹ fun BBC nigba ti wọn n gba wa lalejo ni Ile Ife.
O ni pe: Yato si pe pipa eeyan gẹgẹ bii abobaku tabi bẹẹkọ, Ironu pe Ooni Sijuwade Olubuse ti oun fẹran gan an lọ kuro ni kekere.

Lowa Adimula ni Oba Okunade Sijuwade kuro ni Oba lasan nile Oodua.
O so itan igbe aye rẹ, ohun ti oju rẹ ti ri ki Olorun to gbọ adura rẹ ni aafin Sijuwade ni Ile Ife ki Kabiesi to waja.

Oba Adeyeye Adesiyan mẹnuba ipa pataki ti Olori Ladun aya Ooni sijuwade ko ninu ominira oun kuro ni aafin.
Wo bi ẹni ti a pè ní Abọ́bakú ṣe wa padà di Oba Lowa Adimula! Kini Olodumare ko lèe ṣe?
- Mọ̀ síi nípa Ibeju Lekki nípinlẹ̀ Eko níbí tí wọn kò tí ní iná Mọ̀nàmọ́ná fún ogún ọdún tí Bàálẹ̀ ti ń fa 'Generator'
- Oríire ńlá ló jẹ́ fún àwọn ọmọ Naijiria pé orílẹ̀-èdè yìí ṣì wà ní ọ̀kan ṣoṣo- Buhari
- A ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn tí Igboho, Akintoye àti Ilana Omo Oodua gbé wa síwájú wa- ICC
- Buhari fẹ́ dá Naijiria padà sí ọdún 1984, ṣùgbọ́n a kò ní gbà fun- Femi Falana
- Ọkùnrin márùn-ún tí wọ́n bá lórí kerewà bọ́ sọ́wọ́ Ọlọ́pàá ẹ̀sìn Islam
Mọ̀ síi nípa ohun tó bi àṣà Abọ́baku ati ibi tí ọ̀rọ̀ náà dé dúró báyìí.
Tun wo àwọn Oba mii bí Obalufẹ, Oba Modakeke, Oba Akinlalu atawọn míì tó ń jẹ ni Ile Ife yatọ sí Ooni Ifẹ.

Oríṣun àwòrán, @Ife
Ọjọ kan pere ni wọn ko ki fi n gbe ẹbọ ni Ile Ife
Bẹẹ, ẹṣẹ ko deedee ṣe, o ni nkan to fa a bi Lowa Adimula ṣe ṣalaye.