Yemi Elesho, ìlúmọ̀ọ́ká adẹ́rínpòṣónú jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí 'Ṣé o láyà?'
Ilumọọka adẹrinpoṣonu ni Yẹmi Ẹlẹṣọ, amọṣa lori eto Se o laya tosẹ yii, o da bẹbẹ pẹlu awọn ibeere wa gbogbo.
- Ṣé ẹ̀yin mọ idí ti Abass Akande fi n jẹ Obesere?
- Àwọn ọba Yorùbá kan rèé tí wọ́n rọ̀ lóyè, tí ọba míràn jẹ lójú ayé wọn
- Lóòótọ́ lòògùn owo wà ṣùgbọ́n ayédèrú aláwo ló ń lo ẹ̀yà ara -Ẹlẹ́búìbọn
- Bí Fayemi bá tasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀, àwọn oníbáwí rẹ̀ wà l'Ekiti-Peter Fatomilọla
- Ogun ebi ni Nàìjíríà ń bá fínra lọ́wọ́, ogun coronavirus kò gbọdọ̀ kún un-Oluwo
- Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé Peter Fatomilola ni 'Papa Ajasco' àkọ́kọ́?
Ibeere loriṣiriṣi ni o dojukọ lori eto tọtẹ yii, bi o tilẹ jẹ wi pe ẹnu yii naa ko jẹ ki Yẹmi o gbadun sibẹ, o jẹwọ ara rẹ pe ẹnu nikan kọ loun ni o, oun mọ nipa aṣa ati iṣe Yoruba daadaa.