Akomolede Yoruba: Kí ni ìdí tí aṣọ fi máa ń pọ̀ lára Egúngún ju Orò lọ́?

Àkọlé fídíò, Eégun àti orò, bí wọ́n ṣe jọ bí Ẹ̀ṣà Egúngún nílẹ̀ Yorùba rèé

Ki ni idi ti aṣọ fi maa n pọ lara Egungun ju Oro lọ́?

Idi wo ni Ẹṣa Eegun fi bẹrẹ?

Ki lo de ti ilu Ondo ko ṣe gbudọ jẹ ẹran Okete?

Ẹ gbọ ki lo fa a ti Oloṣun kii jẹ aja, ti ọlọya kii jẹ ẹran agbo?

Gudugudu ni olukọ toni gan funrarẹ ti ko figba kan tura silẹ ninu pipe ẹṣa eegun.

Olukọ lori eto Akomolede ati Aṣatoni ni Olalekan Ojelade ti ileewe Orisumibare Community High School, Ondo.

Olukọ pa itan adayeba pe korikosun ni Eegun ati Oro nigba alaye ti de aye.

Ọgbẹni Olalekan ṣe atupalẹ ohun ti ẹ ko gbọ ri nipa itan Egungun, orin eegun ati ọpọlọpọ nkan to rọ mọ ọ.