Joke Silva: Olu, ó tó gẹ́ pẹ̀lú obìnrin yìí níkan tó ń ba ẹ ṣeré ìfẹ́ nínú sinimá!
Iṣoro pọ ninu igbeyawo mi ṣugbọn kò si ibi ti mo n lọ -Joke Silva
Iriri kọja ẹgbẹ abẹwu, ohun ti agbalagba ri lori ijokoo, Yoruba ni oju ọmọde ko lee too laelae lori iduro.
Agbaọjẹ oṣere, Joke Silva aya Gbajugbaja oṣere Olu Jacob ba BBC Yoruba lalejo ni olu ile iṣẹ wa.

Oríṣun àwòrán, Joke Silva
Bi wọn ṣe ṣe ayẹyẹ ọdun ikarundinlogoji igbeyawo wọn, gbogbo eeyan to fi mọ awọn oṣere akẹgbẹ wọn lo n wari fun bi igbeyawo ọhun ṣi ṣe duro di oni.
Nibẹ ni ogbontarigi oṣere naa ti sọrọ lori ẹsun ifipabanilopọ ti Busola Dakolo fi kan Biodun Fatoyinbo to n dari ijọ COZA.
Joke Silva sọrọ lori igbeyawo oun ati Olu Jacob pẹlu imọran fawọn ọdọ ninu igbeyawo to fi ni lọkan balẹ.
- Kò tọ́ sí Ọlọ́pàá láti ti ọmọ mi mọ́lé tórí ore tó ṣe lásìkò ìwọ́de EndSARS - Iya Eremosele
- Èmi ni mò ń jóko sórí ìtẹ́ Ọlọrun alààyè nílé ayé - Oluwo
- Wo ìdí tí wọ́n fi ta ẹyẹlé kan ṣoṣo ní ₦893,000,000
- Akẹ́kọ̀ọ́ 32 láti Bethel Baptist School gba òmìnira lọ́wọ́ ajínigbé
- Ìtàn Ìjàpá àti ọbọ ni ìjọba àpapọ̀, àwọn agbófinró ń sọ nípa Igboho - Wole Soyinka
- Wo àwọn Fasiti Nàìjíríà tó gbégbá orókè lágbàyé
Ogbontarigi oṣere-binrin yii ṣalaye idi ti oun fi n jẹ Joke Silva dipo Jacob orukọ ọkọ rẹ.
Bakan naa lo sọrọ lori bi o ṣe n ri lara oun ti ọkọ rẹ ba n ba obinrin mii ṣere ifẹ lori sinima.


