Ayo Ewebiyi Mama Oriki: Ọwọ́ Òbí, Ìjọba àti àwọn Ọba ni ìdágbàsókè Yorùbá wà lásìkò yìí

Àkọlé fídíò, Ayo Ewebiyi Mama Oriki: Ọwọ́ Òbí, Ìjọba àti àwọn Ọba ni ìdágbàsókè Yorùbá wà lásìkò yìí

Mama Oriki sọ ọna abayọ ti ko ni jẹ ki ede, aṣa ati iṣẹṣe Yoruba ko parun

BBC Yoruba kan si Ayo Ewebiyi Mama Oriki lati kọ ẹkọ lara bi akewi naa ṣe bẹrẹ aye rẹ ki o le jẹ koriya fun awọn ọdọ asiko yii.

Ayo Ewebiyi Mama Oriki

Mama Oriki sọ bi agbega ede ati aṣa Yoruba ṣe jẹ oun logun pupọ lati kekere aye rẹ.

Ayo Ewebiyi Mama Oriki

Ayo Ewebiyi sọ bo ti ṣe gbe ede ati aṣa Yoruba kaakiri agbaye.

O mẹnuba bi awọn oyinbo ṣe n fẹ wa kọ ede ati aṣa iran Yoruba to dun lede to tun dara laṣa.

Ayo Ewebiyi Mama Oriki

Iró ni pé ẹni tó bá ń kéwì tàbí ṣe ǹkan ìbílẹ̀ kìí sin Olodumare- Ayo Ewebiyi Mama Oriki

Mama Oriki mẹnuba ipa pataki ti awọn agba akewi bii Olanrewaju Adeoju, Ajobiewe ati awọn mii ti ko ki igbega le ba ede Yoruba.

Bakan naa lo sọ pataki ayelujara ti o fi n safihan iṣe ati ede Yoruba kaakiri agbaye.