Ijesha teenager police death: O yẹ kí wọ́n máa yẹ ọpọlọ ọlọ́pàá wò kí wọ́n tó gbà wọn síṣẹ- Nurudeen, baba Monsurat Ojuade
Nínú 'compound' wa ni wọn ti yinbọn fun Monsurat lẹyin ti ọlọpaa naa n pariwo 'I will shoot'.
Awọn Obi, ẹgbọn Monsurat Ojuade ti ọlọpaa kan pa ni agbegbe Ijesha ni ilu Eko ba BBC Yoruba sọrọ lori iṣẹlẹ naa.
Gbogbo ile lo wa nile nigba ti ọlọpaa naa fẹ fi agidi ja wọ inu 'gate' ile awọn Monsura.
- Lébìrà tó jí iriniṣẹ́ iná mọ̀nàmọ́ná a fi ẹgba àtòrì méjìlá ṣara rindin kó lè kọ́ ẹ̀kọ́
- Nítorí ariwo pé àwọn kan fẹ́ pa mi ní mo ṣe sá àsálà fún ẹ̀mí mi kúrò ní Nàìjíríà- Ojọgbon Banji Akintoye
- Ẹ̀yin Òbí, ẹ fi ọmọbìnrin yin sílẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ tó wù wọ́n- Deborah tó ń fi ìlú bàtá àti gángan dárà
- Ìran Yorùbá ló ń fìyà jẹ mẹ̀kúnnù Yorùbá, kò sọ́nà níbi pé kí a pín nítorí...Femi Falana
- Ìdája tí mo fẹ́ ni kí Monsura àti ọlọ́pàá tó pàá jọ lọ padè ní ọrùn láìpẹ́- Adepeju ìyá ọmọ tí ọlọ́pàá pa ní Eko
Ebi rẹ ni pe bi gbogbo eeyan ṣe n sare naa lo jẹ ki Monsurat naa maa sare ni eyi ti wọn si n gbọ ariwo: 'I will Shoot'.
Leyin naa ni wọn ni o yinbon lu Monsurat lẹsẹ ko too maa lọ.
- Ìjọba àpapọ̀ sọ̀rọ̀ lórí bí ọmọ ilẹ̀ Italy ṣe pa ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Naijiria
- 'Ó lé ni akẹ́kọ̀ọ́ 1,000 tí àwọn ajínigbé kó láàrin oṣù kíni sí ìkẹjọ 2021'
- Ìdája tí mo fẹ́ ni kí Monsura àti ọlọ́pàá tó pàá jọ lọ padè ní ọrùn láìpẹ́- Adepeju ìyá ọmọ tí ọlọ́pàá pa ní Eko
- Wo iye àwọn tó ti gbẹ̀mí ara wọn ní Nàìjíríà láàrin ọdún mẹ́rin ìjọba Buhari
- Ìdája tí mo fẹ́ ni kí Monsura àti ọlọ́pàá tó pàá jọ lọ padè ní ọrùn láìpẹ́- Adepeju ìyá ọmọ tí ọlọ́pàá pa ní Eko
Nurudeen Ojuade to jẹ baba rẹ sọ bi wọn ṣe gbee ló sile iwosan mẹta ki ọlọjọ to de nitori idaṣẹsilẹ awọn dokita.
Bakan naa ni Adepeju iya rẹ n beere fun idajọ ododo.
Nigba ti Omolara ẹgbọn rẹ naa sọ ohun ti oju won ri ki aburẹ rẹ Monsurat Ojuade to ku.