Akọ́mọlédè àti Àṣà lórí BBC Yorùbá: Kọ́ síi nípa iṣẹ́ tí oúnjẹ ń ṣe lára níbí

Àkọlé fídíò, Akọ́mọlédè àti Àṣà lórí BBC Yorùbá: Kọ̀ síi nípa iṣẹ́ tí oúnjẹ ń ṣe lára níbí

Iyan lounjẹ, ọka loogun, airi rara la n jẹ ẹkọ...

Oriṣiriṣi ounjẹ ni Yoruba n jẹ fun idagbasoke ara wọn.

Awọn ounjẹ ile Yoruba ni koko ti a n gbe yẹwo lonii lori eto akomolede ati Asa lori BC Yoruba.

Arabinrin Stella Adedeji lati ile iwe CAC Grammar school ni ilẹ Olujii ni ipinlẹ Ondo to wa ni iwọ oorun guusu Naijiria ni olukọ wa fun toni.

Iresi ati ọbẹ

Oríṣun àwòrán, others

Awọn ire oko ilẹ Yoruba pọ, bẹẹ naa si ni irufẹ ounjẹ ti a le ri lara wọn kọ sisọ.

Olukọ wa kọ wa ni kikun nipa oriṣi isọri ounjẹ bii ounjẹ Oniyọ, ounjẹ Ẹlẹran/ Ọlọra, ounjẹ Asemiro, ounjẹ Afaralokun ati ounjẹ amaradan to wa.

gguru

Oríṣun àwòrán, others

Wo awọn nkan ti a le fi ẹgẹ, iṣu ati eree ṣe sii nibi.

Pe awọn ọmọ rẹ ki wọn wa kọ e\kọ loni lori eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba

ounje

Oríṣun àwòrán, others