Akomolede àti Asa lórí BBC Yorùbá: Mọ̀ síi nípa ẹ̀kún ìyàwó níbí

Àkọlé fídíò, Akomolede àti Asa lórí BBC Yorùbá: Mọ̀ síi nípa ẹ̀kún ìyàwó níbí

Koko wo lo wa ninu ẹkun iyawo?

Alagba Tayo Saanuade lati ile iwe Baptist Girl's Grammar School ni Ibadan ni ipinlẹ Oyo ni guusu Iwo oorun Naijiria ni olukọ wa loni.

Eto Akomolede ati Asa lori ikanni BBC Yoruba lo n ṣagbeyẹwo Ekun Iyawo fun ẹyin ololufẹ wa.

Alagba Tayo

Eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba yii n waye pẹlu ajọṣepọ BBC ati ẹgbẹ onimọ YSAN ati ẹgbẹ Akomolede Naijiria lapapọ

Mọ sii nipa akoonu ẹkun iyawo.

Iru ewi wo ni ẹkun iyawo?

Nigba wo ni a n sun ẹkun iyawo?

Awọn wo lo n sun un?

Koko wo lo n jẹyọ nibẹ?

Agbegbe wo lo wọpọ si julọ?

Ẹ wa nkan fidi le ki ẹ wa kọ ẹkọ.

Alagba Tayo