Soyinka Cancer: Àṣe ara mi ni iso ti n run gbogbo bí mo ṣe n ṣèrànwọ́ lórí jẹjẹrẹ

Àkọlé fídíò, Cancer: Àṣe ara mi ni iso ti n run gbogbo bí mo ṣe n ṣèrànwọ́ lórí jẹjẹrẹ

Ko ko koo, "lọdun 2014 bi ana ni arun buruku yii wọle tọ mi wa".

Ọjọgbọn Wole Soyinka ni ṣe loun jẹ ọkan lara awọn to n da ile iwosan silẹ lati ran eeyan lọwọ fun itọju iru aisan bayii, lalai mọ pe iso n run lara tirẹ gan - O ni arun jẹjẹrẹ gbẹdun abẹ.

Wole soyinka
Wole soyinka

Ṣe lootọ ni pe bi eeyan ni arun jẹjẹrẹ, kii ṣe idajọ iku?

Wole Soyinka ni "mo kọ́kọ́ wò ó pé ṣe mo máa tètè fa orí yẹn ni àbí mo fẹ́ kí àrùn yẹn fá a fún mi".

Kó tó wa di pé ẹ̀pa ò bóró mọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n lo ọgbọ́n láti mú ìkìlọ̀ àti ìmọ̀ràn dókìtà akọ́ṣẹ́mọsẹ́ lò.

Ọrọ pọ ninu iwe kọbọ fọnran ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Wole Soyinka.