World Cancer Day 2022: Temitope Alao Sanni: Wo bí o ṣe lè máà yẹ ọmú rẹ̀ wò láti dènà àrùn jẹjẹrẹ

Àkọlé fídíò, Jejere

Oni, ọjọ kẹrin, oṣu keji, ọdun 2022 ni ayajọ arun jẹjẹrẹ ni agbaye.

Oriṣii arun jejere lo wa ati pe oriṣii ẹya ra lo ti maa n mu ẹda laye.

Akọṣẹmọṣẹ nipa ohun jije ati iwulo wọn lara, Temitope Alao Sanni gbalejo BBC Yoruba.

Arun jejere oyan

Temitope sọrọ nipa irufẹ ounjẹ ati eso ati ewebẹ to n fa arun jẹjẹrẹ ati awọn eyi to dara lati maa jẹ.

Bakan naa lo gba awọn obinrin ni mọran lati tete gbe igbesẹ itoju to ba yẹ ni kete ti wọn ba ti mọ pe awọn ni arun jẹjẹrẹ ọyan.