Oba Adeyemi Obalanlege, Olota ti Ota: Àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà ṣetán láti kọ́ ẹ̀kọ́ ṣùgbọ́n ìjọba kò ṣe tó ní ìwà ọmọlúwàbí ṣe ń sọnù- Oba Olo

Kò rọrùn láti jẹ́ ọmọlúwàbí lásìkò yìí nítorí pé kò sí iṣẹ́, owó, àti aàbò fún ọ̀dọ́- Olota ti Ota nipinle Ogun
Oba Adeyemi Obalenge sọrọ ni kikun nipa ajọṣẹpọ to wa laarin rẹ ati Oba Alaafin Adeyemi Keta ti Oyo ati Oba Alake ti ile Egba,
- Àwọn ọba Yorùbá kan rèé tí wọ́n rọ̀ lóyè, tí ọba míràn jẹ lójú ayé wọn
- Kí ló fà ogun Ìjàyè àti ìṣubú Kurunmi, ìfẹ́ ìlú ni àbí orí kunkun?
- Duro Ladipọ, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà àti ọmọ àlúfà tí kò gbàgbé àṣà ìbílẹ̀
- Ìtàn ìgbésí ayé Oshodi, ọmọ Tápà léǹpe tó di akọni ní ìlú Eko
- Ìtàn Manigbagbe: Àwọn àjakalẹ-àrun to ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus
- Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré Yorùbá tí kìí ṣe ọmọ káàárọ̀ oòjíire
- Ǹjẹ́ o mọ àwọn òṣèré bí Oyin Adejọbi, Funmi Martins àtàwọn míì tó ti dágbére fáyé?
Kabiesi ni pe ko si ija laarin awon mẹtẹẹta yatọ si bi àwọn kan ṣe n pariwo lori ayelujara pe aarin awọn ko gun.
O ni pe iyapa ero ti oun pe ni 'Policy difference' lo le wa ni eyi to si di dandan nitori pe eyi wu mi ko wu ọ ni kii jẹ ki tegbọn taburo fẹ obinrin kan naa.
- Fayemi ni Bàbá ìsàlẹ̀ gbogbo APC ni Ekiti, kìí ṣe fún èmi nìkan- Abiodun Abayomi Oyebamiji
- Dangote, má ṣe dáwọn ọ̀dọ́ tó ní kó dupò ààrẹ lọ́dún 2023 lóhùn o- Shehu Sani
- Musulumi àti Kristẹni lo ṣe àdúrà níbi ètò ìsìnkú Timothy Adegoke lónìí
- Àwọn nǹkan mẹ́ta tí a kò tíì mọ̀ nípa Covid-19 lẹ́yìn tí àrùn náà bẹ́ sílẹ̀ rèé
- Wo Mẹkáníìkì alápá kan tí ayé ń pariwo pé o mọ ìjánu ọkọ̀ ṣe púpọ̀
- Àwọn ọlọ́pàá ti parí ìwádìí ikú Timothy Adegoke, ká lọ sílé ẹjọ́ pẹ̀lú afurasí mẹ́fa tí wọ́n mú ló kù báyìí- Agbejoro Timothy
Oba Adeyemi Obalanlege mẹnuba iwa itẹriba gẹgẹ bii ọkan lara iwa ọmọluwabi to yẹ ki ọdọ ni.
Bakan naa lo sọrọ lori ohun to ṣokunfa iṣoro pe iwa ọmọ luwabi n sọnu ni Naijiria bayii.
Ẹ̀yin eèyàn náà lẹ̀ ń fi ẹnu da àárin àwọn Oba Aládé ilẹ̀ Yorùbá rú, ó tó gẹ́- Oba Adeyemi

Oríṣun àwòrán, Others
- Wo bí wọ́n ṣe sin Ọba Satani pẹ̀lú ọkọ̀ àti orin tó fẹ́ràn jù
- Ọba Lamidi Adeyẹmi, òṣìṣẹ́ adójútòfò àti Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò kó tó jọba
- Mọ̀ síi nípa ìṣẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ ríru tó mú ẹ̀mí 16,000 èèyàn lọ tó sì ba dukia $206b jẹ́
- Àwọn Oba Yorùbá kan rèé tí wọ́n rọ̀ lóyè, tí Oba míràn jẹ lójú ayé wọn
- Kò sí iṣẹ́ tó lè pa owó wọlé tó iṣẹ́ ọnà tí mo ń ṣe yìí- Femi Babalola
Oba Adeyemi Obalanlege di ẹru ẹbi naa le ijọba lori pe wọn ko nawo si eto ẹkọ to bi o ti yẹ.
Ati pe, iṣoro eto aabo ati airise ṣe n ṣakoba pupọ fun awọn ọdọ naijiria lasiko yii.