Sikiru Alabi: Àṣìṣe awakọ̀ ló sọ mi dí alápá kan ṣùgbọ́n mo kọ̀ láti tọrọ bárà fi jẹun
Sikiru Alabi, gbajugbaja mọkaniiki to n tun ijanu ọkọ ṣe gbalejo BBC Yoruba.
Alabi ṣalaye ijamba ọkọ ni ijebu Ode ni ipinle Ogun to sọ ọ di alapa kan.
O menuba bi oun ṣe kọ lati ma tọrọ owo fi jeun ti oun fi gbajumọ iṣẹ ti o n ṣe di isiyin.
- Àwọn àgbà oyè Ibadan fẹnukò láti gbé ẹjọ́ kúrò nílé ẹjọ́
- Mo gba kádàrá pé mi ò lè bímọ nílùú tó jẹ́ pé ọmọ pọ̀ lára àwọn obìnrin
- Ìkọlù darandaran àti àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ògùn: Ènìyàn márùn-ún, ọ̀pọ̀ ilé bá ìṣẹ̀lẹ̀ náà lọ
- Kí gan-an là n pé ní Voodoo?
- Ìdìbò 2023: Àwọn ìpèníjà tí Bola Tinubu yóò kojú nínú ìrìnàjò rẹ̀ nìyí
- Ẹgbẹ́ òṣèlú APC ti pín l'Osun, báyìí ni ọ̀rọ̀ ṣe di gbas gbos láàrin Aregbesola àti Oyetola
Sikiru Alabi sọrọ nipa ipenija rẹ to n koju lẹnu iṣẹ naa .
Bakan naa ni BBC Yoruba ba awọn onibara rẹ sọrọ ti gbogbo won si gboriyin fun Sikiru pe o mọ iṣẹ rẹ daadaa.
- Wo awọn iroyin manigbagbe to waye ni ọsẹ yii
- Mọ̀ sií i nípa Oba Yesufu Asanike , Olubadan tí kìí fi ọ̀rọ̀ sí abẹ́ ahọ́n sọ kódà níwájú sọ́jà
- Àkójọpọ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó dára àti èyí tó burú tó wáyé ní 2020
- Ọba Lamidi Adeyẹmi, òṣìṣẹ́ adójútòfò àti Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò kó tó jọba
- Àwọn àwòrán ìṣẹ̀lẹ̀ tó làmìlaaka láti ilẹ̀ Áfríkà l'ose tó kọjá