Dangote for president? Shehu Sani rọ Dangote láti kọ etí ikún sáwọn ọ̀dọ́ tó ní kó dupò ààrẹ lọ́dún 2023

Aliko Dangote ati Femi Otedola

Oríṣun àwòrán, Femi Otedola

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Sẹnẹtọ ẹkun arin gbungbun ipinlẹ Kaduna tẹlẹ, Shehu Sani ti gba gbajugbaja oniṣowo, Aliko Dangote ni imọran lati kọ eti ikun sọrọ awọn ọdọ Arewa ti wọn ni ko dupo aarẹ lọdun 2023.

Sani rọ Dangote pe ko gbajumọ ileeṣẹ epo ifọpo rọbi to n kọ si ipinlẹ Eko ko si ri pe o pari rẹ.

Sẹnẹtọ Sani sọ pe ti Dangote ba le dasi ọrọ oṣelu, o ṣeeṣe ki o ṣe akoba fun iṣẹ ileeṣẹ ifọpo-rọbi to n kọ lọwọ lara.

Ohun ti awọn ọdọ Arewa sọ ree

Ẹgbẹ awọn ọdọ ẹkun ariwa orilẹede Naijiria labẹ, Arewa Youth Assembly kepe Dangote ati awọn ilumọọka oniṣowo mii atawọn akọṣẹmọṣẹ lati dasi ọrọ ibo aarẹ ọdun 2023.

Ẹgbẹ naa ni iriri wọn yoo ṣe iranwọ lati mu ilọsiwaju ba orilẹede Naijiria.

Àkọlé fídíò, Fatimah Abode Lybia

Ninu atẹjade ti ẹgbẹ naa fi sita eleyii ti akọwe apapọ rẹ, Desmond Minakaro ati abẹnugan ile, Mohammed Salihu Danlami buwọlu sọ pe awọn eeyan bi Dangote, Femi Otedola, Mike Adenuga, Akinwumi Adesina, Herbert Wigwe, Ngozi Okonjo Iweala ati bẹẹ bẹẹ lọ lo koju osuwọn lati dupo aarẹ Naijiria.

Àkọlé fídíò, Eba

Wọn ni awọn oniṣowo ti wọn mọ bi eeyan ṣe ṣowo jere lo yẹ lati dari Naijiria bayii.

Ẹgbẹ Arewa ni ọrọ aje ko ni ṣai gbooro ti iru wọn ba jẹ aarẹ, bakan naa ni awọn eeyan yoo ri iṣẹ ṣe nitori awọn gan na ti gba ọpọ eeyan ṣiṣẹ fun ra wọn.

Àkọlé fídíò, Sikiru Alabi

Ẹgbẹ naa tun rọ awọn ọmọ Naijiria lati kọ eti ikun esi awọn oloṣelu to maa n fun wọn ni raisi, ọsẹ ifọṣọ ati ẹgbẹrun kan naira lasiko idibo ki wọn si dibo fawọn to le tun Naijiria ṣe.

Amọ, Sẹnẹtọ Shehu Sani ti sọ pe ko si ọrọ nibẹ rara, o ni ki Dangote gbajumọ owo to n ṣe.

Àkọlé fídíò, Olùdíje gómìnà APC

Kinni lawọn eeyan n sọ lori ayelujara si imọran Shehu Sani?

Isha Fola, Joshua Obera, Jibra'eel pẹlu @Sirdotskill sọ loju opo Twitter wọn pe Dangote atawọn ilumọọka oniṣowo yii le ma wọle ni wọọdu wọn ti wọn gbeba ibo.

Wọn ni ọtọ oṣelu ṣiṣe yatọ gede gede si iṣẹ oniṣowo tori ohun to ba jọra ni a maa n fi we ara wọn.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Amọ, eeyan perete ni wọn sọ pe awọn eeyan bi Dangote ni Naijiria nilo lasiko yii lati de ilẹ ileri.

Wọn gbagbọ pe awọn ni ko le ṣe aṣeti ni ijọba ati pe wọn ti lowo ti wọn tẹlẹ, eyi ko ni jẹ ki wọn kowo jẹ.

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5

Skip X post, 6

End of X post, 6

Skip X post, 7

End of X post, 7

Skip X post, 8

End of X post, 8