Femi Babalola: Mo tá iṣẹ́ ọnà kan ni mílíọ̀nù kan rí, kódà mo n fi egungun ẹja, irin, amọ̀ àti igi dárà tó wù mí

Àkọlé fídíò, Femi Babalola to n fi irin ṣe iṣẹ ọna

Kò sí iṣẹ́ tó lè pa owó wọlé tó iṣẹ́ ọ̀nà tí mo ń ṣe yìí- Femi Babalola

Femi Babalola to n siṣẹ agbegilere lo gba BBC Yoruba lalejo.

O sọ bi o ṣe bẹrẹ irinajo rẹ lati kekere to n ba awọn akẹgbẹ rẹ ṣe iṣẹ amurele to dẹ n gba owo lọwọ wọn.

Femi Babalola sọ nipa bi oun ṣe n lo ọpọlọ fi ṣe iṣẹ ọna to wu u.

O n i inu Baba oun ko kọkọ dun si iṣẹ naa ti oun n ṣe.