Jẹ́ ká lọ sílu mi: Kò sí ìtàn Ibadan láìsí Efunsetan, Òkè méje, Bower's Tower àtàwọn ǹkan míì
Wo ibi ti ogun le awọn eeyan Ibadan dé bayii ati ireti wọn lọjọ ọla.
BBC Yoruba lọ silu Ibadan to jẹ olu ilu ipinlẹ Oyo to wa ni guusu iwọ oorun Naijiria.
Awọn Ibadan kii ṣe eeyan lasan ninu itan iran Yoruba.
Opolopo ogun abẹle ati ogun ilu ni wọn ti ja ti wọn si ti bori sẹyin.
- Ìran Yorùbá ló ń fìyà jẹ mẹ̀kúnnù Yorùbá, kò sọ́nà níbi pé kí a pín nítorí...Femi Falana
- Báwo ni mo ṣe lè sọ̀rọ̀ ìtùnú fún ẹni tí ọ̀kan rẹ̀ dàrú?
- Ta ni Orunmila? Kíni pàtàkì mímọ̀ nípa Ifa fún ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro ẹ̀dá láyé?
- Ìdájọ́ tí mo fẹ́ ni kí Monsura àti ọlọ́pàá tó pàá jọ lọ padè ní ọrùn láìpẹ́- Adepeju ìyá ọmọ tí ọlọ́pàá pa ní Eko
- Ẹ̀yin oníṣègùn ìbílẹ̀, ẹ bá wa ṣe àwárí oògùn àjákálẹ̀ àrùn covid-19- Ìjọba Naijiria
- Iléeṣẹ́ ìjọba, ẹ yé ra ọkọ̀ tòkunbọ̀ fàyàwọ́ mọ́- Ajọ Customs kìlọ̀

Oloye Lekan Alabi, Agbaakin ti ilẹ̀ Ibadan salaye ni kikun lori itan ilu Ibadan.
A de aafin Aboke naa nibi ti baba aboke ti sọ ona ti Ibadan fi n bori ogun to n ja wọn.

BBC Yoruba de awọn agbegbe to ṣe koko ninu itan Ibadan ki ẹ le mọ wọn.
Je ka lo silu mi ti osu yii kun fọfọ ni.

- Akinwumi Isola dárà nínú ìwé "Nítorí Owó" lórí Akomolede Yoruba
- Àwọn Olùkọ́ Akure pegedé lórí ètò Akomolede àti Aṣa lórí BBC Yorùbá
- Wo ìtàn bí ààlọ́ ṣe bẹ̀rẹ̀ àti onírúurú ààlọ́ àpagbè àti àpamọ̀
- Wo ìyàtọ̀ tó wà láàrin Ìjálá, Ìrèmọ̀jé àti oríkì ọ̀pọ̀ ẹranko ijù
- Ṣé o rántí eré òṣùpá? Wo èré ìdárayá èyí tó yẹ fún àárọ̀ kùtù àti èyi tó wà fún òṣùpá
- Àwọn Olùkọ́ Yorùbá ní ìlú Ondo fọkọyọ lórí ètò Akọ́mọlédè àti Àṣà lórí BBC Yorùbá
- Agbọ́nmágbọ́ntán, Agọ̀mágọ̀jù, mọ̀ síi nípa àwọn orúkọ Ìjàpá nínú alọ àpagbè Yorùbá