Smuggled vehicles: Àjọ aṣóbodè kìlọ̀ fáwọn iléeṣẹ́ ìjọba láti dẹ́kun ríra ọkọ̀ tòkunbọ̀ fàyàwọ́

Oríṣun àwòrán, NCS
Ajọ aṣọbode, Nigeria Customs Service (NCS) ti kilọ fawọn ọmọ ile igbimọ aṣoju-ṣofin pe ọpọ awọn ọkọ ''escort'' ti wọn lo ni ileeṣẹ ijọba lo jẹ ọkọ fayawọ.
Igbakeji ọga agba ajọ aṣọbode ni Naijiria, Aliyu Saidu lo ṣalaye ọrọ yii.
''O ṣeni laanu pe awọn eeyan pataki lo n lo ọkọ Hilux tawín oni fayawọ gbe wọ Naijiria.
- Ẹ̀yin oníṣègùn ìbílẹ̀, ẹ báwa ṣe àwárí òògùn àjákálẹ̀ àrùn covid-19- Ìjọba
- Àwọn jàndùkú jí Emir Bungudu gbé, wan pa ọlọ́pàá lọ́nà mọ́rosẹ̀ Abuja sí Kaduna
- 'Màmá mi, Iyabo Oko ti ní "Left Stroke" ní fọ́tò wọ́n ṣe rí bẹ́yẹn o àmọ́...'
- Sunday Igboho ránṣẹ́ tuntun nípa agbẹjọ́rò rẹ̀ ní Benin republic, Ó ní...
- Atọ́kùn egúngún, ọmọ rẹ̀ àti èèyàn méjì àtìmọ́lè lórí ẹ̀sùn ìpànìyàn ní mọ́ṣálááṣí
- Eèmọ̀ wọ̀lú, ẹni tó ń ta ọtí àti ògógóró gún Oníbárà rẹ̀ pa ní Osun!
- Ìwọ́de Yoruba Nation lólú iléeṣẹ́ àjọ UN wáyé, bó ṣe lọ nìyí
Ti ẹ ba wo ori ẹrọ kọmputa wa, ko si akọsilẹ ọkọ Hilux dabi alara ninu akọsilẹ wa.
Ṣugbọn ọkọ Hilux yii pọ yanturu ni igboro eyi to tumọ si pe awọn eeyan ko maa ra awọn ọkọ naa nipasẹ ajọ aṣọbode mọ.
Ọpọ owo to yẹ ki awọn eeyan maa san fun ijọba lori awọn ọkọ yii ni wọn ko san.
Eleyii tumọ si pe wọn ja ijọba lole ni.
Mo fẹ sọ fawọn ọmọ Naijiria pe Aarẹ Muhammadu Buhari nikan lo lagbara lati maa sanwo ori ọkọ lati oke okun wọ Naijiria,'' Saidu ṣalaye.
Igbakeji ọga agba ajọ aṣọbode ni Naijiria ile aṣofin lati gbe ofin kalẹ ti yoo mu ni dandan fawọn eeyan lati maa gba iwe ọkọ ti wọn fẹ ra ki wọn to raa.
- Wo ọ̀nà méje tí o lè fi dáàbò bò ọmọ rẹ níbàyìí tí iléẹ̀kọ́ ti bẹ̀rẹ̀ padà
- Kókó nǹkan tí ẹgbẹ́ NINAS ń bèrè fún ní ibi ìpàdé UN General Assembly
- Sunday Igboho ránṣẹ́ tuntun nípa agbẹjọ́rò rẹ̀ ní Benin republic, Ó ní...
- Èmi tí wọ́n kọ́kọ́ pé ọkọ Bimbo kú gàn an ti di jálajála lórí ìròyìn burúkú náà- Jaye Kuti, ọ̀rẹ́ Bimbo Oshin
- Eèmọ̀ wọ̀lú, ẹni tó ń ta ọtí àti ògógóró gún Oníbárà rẹ̀ pa ní Osun!
- Ìwọ́de Yoruba Nation lólú iléeṣẹ́ àjọ UN wáyé, bó ṣe lọ nìyí















