John Amanam: Ìfẹ́ tí mo ní sí àbúrò mi ló sọ mi dí ẹni tó ń ṣe 'Prosthetic' báyìí

Àkọlé fídíò, John Amanam: Ìfẹ́ tí mo ní sí àbúrò mi ló sọ mi dí ẹni tó ń ṣe 'Prosthetic' báyìí

Diedie ni mo kọ lati maa lo ọwọ mi tuntun to jẹ ti alawọ dudu- Sunday

Agbegilere ati amọkoko ti tun igbesi aye awọn eeyan ṣe

Ubokobong Amanam Sunday ni ina ọdun bu gbamu mọ ọ lọwọ ni ọdun ku ọla lo ba sọọ di alaabọ ara ni eyi to n mu itiju dani.

Egbọn rẹ, John to n ṣiṣẹ awọn to n ṣe ara loge lẹyin itage ninu ere lo ba a wa ọna abayọ si iṣoro rẹ.

John salaye fun BBC nipa igbiyanju rẹ lati maa pese ẹya ara atọwọda fun awọn alawọ dudu ni eyi to ba aawọ ara wọn mọ.

Sunday ni igbiyanju obi oun lati ra ẹya ara atawọda lati Germany ko ba aawọ ara ohun mu ki ẹgbọn rẹ to ṣe eyi to n lo fun un.