End bad government: Wọn rò pé a maa jà tàbí ba ǹkan jẹ́ ni ṣùgban ọmọlúwàbí ni wa-Afẹ̀hónúhàn
Ile ijọba ni alausa ni Ikeja ni awọn eeyan yii ti ranṣẹ si ijọba lori ohun to n dun wọn nipa ifiyajẹni lọna aitọ.
End bad government: Wọn rò pé a maa jà tàbí ba ǹkan jẹ́ ni ṣùgbọn ọmọlúwàbí ni wa-Afẹ̀hónúhàn
Onikaluku sọ diẹ nipa ohun ti oju wọn ti ri lọwọ awọn agbofinro Naijiria.
Wọn ni ọrọ yii kii se ti ija bi ko ṣe pe ijọba ṣe ohun to yẹ.
- Wo àfiwé owó oṣù Ọlọ́pàá Nàìjíríà pẹ̀lú akẹgbẹ́ wọn lókè òkun
- Buhari, Makinde, Sanwo-Olu kẹ́dùn pẹ̀lú ẹbí Tola Oyediran, àkọ́bí lóbìnrin tí Obafemi Awolowo bí tó papòdà
- Báwo ni Donald Trump ṣè ń rí ọwọ́ mú sí nínú àkójọ èrò àwọn olùdìbò?
- Wo àwọn Ṣọ́ọ̀ṣì Nàìjíríà àti l'Áfíríkà tó ń wólẹ̀ àdúrà kí Trump lè wọlé ìbò ààrẹ America
- Sọ̀rọ̀ sókè! Odunlade, Toyin, Ijebu dásí ìwọ́de #EndSARS, Mercy Aigbe gbébọn
- Ọkọ̀ akẹ́rù tí ìjánu rẹ̀ já ló kọlù ọkọ̀ agbépo tó fa ìjàmbá iná ní Otedola- LASEMA
