Akomolede ati Aṣa lori BBC: Mọ̀ si nípa oríṣìí ẹ̀ka ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ àti ìwúlò wọn
BBC Yoruba tun ti de laarọ yii lati la wa lọyẹ nipa ẹkọ ede Yoruba lori eto wa Akọmọlede ati Aṣa.
Lọsẹ yii, aya Adeyemo ni yoo maa kọ wa lẹkọọ nipa Isọri ọrọ ninu gbolohun Yoruba ati itumọ rẹ.
- Ẹ wá dánrawò níbí pẹ̀lú Àpólà Ọ̀rọ̀ Orúkọ, "Noun Phrase"
- Ẹ̀yin tí ẹ kò gbọ́ Yorùbá, ẹ ṣúnmọ́ bí láti kọ́ lítíréṣọ̀ èdè Yorùbá lórí BBC
- Àṣà Oge Ṣíṣe ní Akọ́mọlédè BBC Yorùbá ń gbé yẹ̀wò lónìí, Ó yá, iṣẹ́ ti bẹ̀rẹ̀...
- Wo àànfàní ‘Masturbation’, fífún ara rẹ̀ ní adùn ìbálòpọ̀
- Hubert Ogunde rèé, baba àwọn òsèré tíátà
Bakan naa ni yoo sọ fun wa orisi isọri ọrọ to wa, ba se n lo wọn ati anfaani wọn.
Ẹ wa kọ ẹkọ pupọ nipa asa ati ede wa, ko maa baa parun.