Àkọlé àwòrán, Awọn ẹyọ ti a mọ si ti ìlú Eko náà kò gbẹ́yìn lásìkò ọdún Osun Osogbo
Àkọlé àwòrán, Awọn olùbọ Omi Osun Osogbo ń lọ ojúbọ
Àkọlé àwòrán, Awọn ero ìwòràn ní ojúbọ Osun osogbo
Àkọlé àwòrán, Arugba àti Awọn èrò nibi Osun Osogbo
Àkọlé àwòrán, Aarẹ Ọna Kankanfo, Oloye Gani Adams ati adari ileeṣẹ aṣa, Nike Art gallery naa ti wa ni ikalẹ.
Àkọlé àwòrán, Awon alawo funfun ti won wa yẹ ayẹyẹ ọdún náà
Àkọlé àwòrán, Aworan lati ibi ojubọ. yatọ si Oloye Gani Adams, Baba Yẹmi Ẹlẹbibọn ati awọn eekan mii, a ṣi n reti awọn alejo pataki mii gẹgẹ bi eto naa ṣe gbinaya.
Àkọlé àwòrán, Odun yii dun o lárinrin, awon alawo funfun péju láti bọ Osun Osogbo
Àkọlé àwòrán, Àtàọjá àti àwọn olori níbi ayẹyẹ Osun Osogbo, ètò si ti gbera sọ
Àkọlé àwòrán, Awọn lẹgbẹlẹgbẹ-loyeloye ati ọkanọjọkan ẹgbẹ lawujọ ti n ṣe ikini sí Kabiyesi Ataọja ti ilu Ọṣogbo Ọba Jimoh Oyetunji, Kabiyesi naa si n wure fun wọn.
Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn oba aláde ti kò lè yọjú síbi ayẹyẹ náà fi ọ̀pá àṣẹ wan ránṣẹ́
Àkọlé àwòrán, Awọn aláwọ̀ funfun náà wá láti ṣe ọdún Osun Osogbo
Àkọlé àwòrán, Tarúgbó tomidan lo peju ni bi ayẹyẹ ti wọ́n sì ń reti iwúre àtàọjà
Àkọlé àwòrán, Awọn àgbààgbà obinrin náà rèé oo, ninu aṣọ òfì àti leesi ẹgbẹ́jọdá