Unai Emery di akọnimọọgba Arsenal

Aworan Unai Emery ati Ivan Gasidis

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Unai Emery nibi afihan re pelu asaaju Egbe Arsenal Ivan Gasidis
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Unai Emery ni akọni moogba tuntun fun ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal.

Ẹgbẹ náà fi ìkéde iyansipo rẹ ati ìkínni káàbọ̀ sójú òpó Twitter wọn.

Emery n darapo mọ ẹgbẹ Arsenal láti PSG níbi tí ọ ti gbà ìfé ẹyẹ liigi pẹlú wọn.

Aworan Unai Emery

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Unai Emery ni akonimoogba akọkọ ti Arsenal gba lẹyin ọdun mejilelogun

Bákannáà ni o tí gbà ife ẹyẹ Europa league pẹlú Sevilla ni ẹẹmẹta otooto.

Emery ni inú oun dun lati dárapo mọ ẹgbẹ Arsenal.

O sọ pe oun sí ní ìrètí pé ''àwọn yóò jo ṣé gudugudu meje ati yaya mẹfa pọ''

Àwọn ololufe ẹgbẹ Arsenal ni orílè-èdè Nàìjíríà, si ti n fi iṣẹ ìkínni káàbọ̀ ranṣẹ sí akoni-moogba tuntun wọn

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3