Ọlọpaa Ìpínlẹ̀ Osun tí fojú àwọn afurasí mọ́kàndínlógójì 39 hàn síta

Ọlọpaa Ìpínlẹ̀ Osun là bẹ CP Patrick Longe tí fi ojú àwọn afurasi lè dé. E yìí ló wáyé ní bí orí Ilésẹ to wa nílùú Osogbo nipinle O
Ọga Ọlọpaa Ìpínlẹ̀ Osun, Arábìnrin Yemisi Opalola ba Ikọ BBC news Yorubá sọ̀rọ̀ lórí àwọn afurasi yìí.
O ni wí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí ọwọ́ bá nínú àwọn afurasi yìí ni àwọn n tí wá wọn tí pẹ̀ nitori àwọn tí àwọn afurasi yìí ṣe ìkọlù sọ́dọ̀ wón ní wọn tí mú ẹ̀sùn yìí wá ti àwọn sí ṣe iṣẹ́ lórí rẹ.
Bakan náà ló tesiwaju nínú ọ̀rọ̀ pé, oríṣiríṣi ni ìwà tí àwọn afurasi yìí wù, bí ìwà dada èèyàn lọ́nà àti gbà ọkọ̀ àti láti lọ sí ilé onílé láti lọ gbá ọkọ̀ bá kan náà, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹlòmíràn lára ló ṣe ayé deru ìwé irinna ọkọ̀ àti naaba idà ọkọ̀ mọ àti bẹẹ bẹẹ lọ.
Nígbà tí Ikọ yìí ni àǹfààní láti bàa Eyitayo Emmanuel tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn afurasi yìí, óun lọ jẹ́ ọmọ bibi ìlú IKirun nipinle Osun òun ló jẹ́ ọmọ ọdún Mokanlelogbon 31 years ló ṣàlàyé pé òtítọ́ ni ohun jí ọkọ̀ náà gbé
Bákan náà ni Olúwasanmi Adebamjo tó ọmọ bibi ìlù IKirun nipinle Osun tí ọjọ́ orí rẹ jẹ ọmọ ọdún Marunlelodun 25 years ló jẹ́ wọ pé ohun àti àwọn ẹgbẹ́ òun àwọn ja olè ni tòótọ́, tí ó sì ra ọwọ ẹ̀bẹ̀ sì ìjọba kí wọ́n kó sì ju àánú wo òun.
Lawal Ọmọtayọ ló ti jẹ wọ́ pé òhun ṣe ayé deru naaba ọkọ̀ àti ayé deru ìwé irinna ọkọ̀ fún àwọn ènìyàn tí kò bá ní agbára láti lè san owó èyí tó jẹ́ gidi.
Azeez Ayobami ló sọ wí pé oun tí ṣe ayé deru ìwé ọkọ̀ àti naaba idà ọkọ̀ mọ fún àwọn èèyàn bíi mẹwaa.
Alukoro àwọn Ọlọpaa Ìpínlẹ̀ Osun Yemisi Opalola tí sọ pé gbogbo àwọn afurasi yíi ni yóò fi ojú bá ilé ẹjọ́.
Bẹ́ẹ̀ ni ó pàrọwà fún gbogbo olùgbé Ìpínlẹ̀ Osun kí wọ́n kó fọwọ́ sọ wọ́ pọ pẹ̀lú àwọn Ọlọpaa kí ìwà ibajẹ lè dii òun ìgbàgbé pátápátá.












