Wo èrò àti àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tí àwọn olùgbé Gaza ṣe fún BBC

Àkọlé fídíò, Wo èrò àti àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tí àwọn olùgbé Gaza ṣe fún BBC

Ariwo ko si ibi ti a le lọ ni pupọ awọn olugbe Gaza ni pariwo lẹyin ti ikọlu orilẹede Israeli ṣe si ilu naa to ti gbe ẹmi awọn to si sọ ọpọ di lai ni ile lori.

Yato si pe gbe ile lori awọn eeyan, ọpọ lo wa ni ile iwosan bayii lẹyin ti wọn farapa yanayana.

Awọn eeyan to n gbe niluu Gaza ti n ṣe akọsilẹ igbeaye wọn lasiko ibugbamu.

Fọnran yii sọ itan eeyan meji laarin wọn.

Khalid Motawa, olugbe Jabalia niluu Gaza n ba BBC sọrọ pẹlu ibẹru to si jẹ ko di mimọ o to eeyan mọkanlelọgbọn ninu mọlẹbi to ti jade laye.

Farida Adel, ti oun naa jẹ olugbe Gaza ni ọpọ awọn to jẹ ọrẹ oun ni oun ri mọ to si ṣesẹ ki ọpọlọpọ ti jade laye.

Aworan Farida Adel Olugbe Gaza