Sowore: Ilé ẹjọ́ pàṣẹ kí ìjọba àpapọ̀ san ₦1m owó ẹ̀bẹ̀ fún ẹgbẹ́ ajijagbara Sowore, torí ìwọde wọn tí wọ́n dà rú

Ọmọyẹle Ṣoworẹ ati ọlọpaa kan duro

Oríṣun àwòrán, omoyele sowore

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 10

Ilé ẹjọ́ gíga tí ìjọba àpapọ̀ tó wà n'ilu Eko ti pàṣẹ fún ìjọba láti san mílíọ̀nù kan náírà fún ẹgbẹ́ ajijagbara Revolution Now, lórí bo se da ìwọde ẹgbẹ́ náà ru ni ọjọ́ Kàrún oṣù Kẹjọ ọdún 2019.

Agbẹjọro kan tó kopa ninu ìwọde náà, Olukoya Ogungbeje, ló wọ ìjọba lọ sílè ẹjọ́, lórí ẹ̀sùn pé àwọn òṣìṣẹ́ alaabo yín afẹ́fẹ́ tajú-tajú sì òun àti àwọn èèyàn yókù to ń ṣe ìwọde lójú.

Ilé ẹjọ́, tó ní Ogungbeje jàre ẹjọ́ ọhun, tún pàṣẹ fún ìjọba àpapọ̀ láti tọrọ aforijin lọ́wọ́ olupẹjọ náà, lójú ewé ìwé ìròyìn mẹta nilẹ wá.

Adajọ Maureen Onyetenu, tún kéde pé bí ijọba àpapọ̀, láti ipasẹ àwọn Ọlọpaa ṣe da ìwọde náà ru "kò bófin mú, ìwà ìjẹgàba ni, kò bá ìlànà ìjọba alagbada mú, tó sì tún tako àmúlò òfin ilẹ wa".

Ọmọyẹle Ṣoworẹ atawọn ọlọpaa ati awọn agbẹjọro kan duro

Oríṣun àwòrán, omoyele sowore

Bákan náà ni adajọ Onyetenu gbà pé, ìjọba fi ẹtọ Ogungbeje to pé ẹjọ́ ní orúkọ àwọn Oluwọde yoku dùn wọn, nítorí abala kejidinlogoji, ikokandinlogoji àti ogójì òfin ilẹ̀ wá ti ọdún 1999, tí fun wọn ní àǹfààní

láti ṣe bẹ́ẹ̀.

Adajọ náà tún korò ojú sì bí awọn agbofinro ṣe gbé àwọn oluwode náà lọpọ yanturu, tá àbùkù wọn, fín afẹ́fẹ́ tajú-tajú sì wọn lójú àti fífi wọn sínú túbú.

Obìnrin kan lu ọ̀gá ọlọ́pàá, ó tún gé ọmọ'ṣẹ́ ọlọ́pàá jẹ nítorí òfin ìséde ní Eruwa

Ọlọpaa fẹ mu ọlọkada kan

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Ọga patapata fun ileeṣẹ ọlọpaa lorilẹ€de Naijiria, Mohammed Adamu ti ke si araalu pe ẹnikẹni to ba ṣiwọ lu ọlọpaa to wa lẹnu iṣẹ rẹ yoo jẹ iyan rẹ niṣu ni.

Ọga ọlọpaaAdamu sọ ọrọ yii ninu esi rẹ lori arabinrin kan to kọlu ọga ọlọpaa kan ni ilu Eruwa ni ipinlẹ Ọyọ.

Ọga ọlọpaa naa ti wọn pe orukọ rẹ ni ASP Adeyẹmọ Ogunyẹmi lo lọ si agbegbe Gbọlaguntẹ Okeọola ni Eruwa iyẹn nijọba ibilẹ Ibarapa East ni ipinlẹ Ọyọ lati lọ fidi ofin konile o gbele mulẹ nibẹ.

Nibẹ ni arabinrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Kẹhinde Afolakẹ ti kọluu to si soo laṣọ mu. Igbaju igbamu ni arabinrin naa fi ṣe ọga ọlọpaa naa lọjọ.

Ẹ wo fidio naa:

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Ọga ọlọpaa lorilẹede Naijiria tun ṣalaye siwaju sii pe nigba ti wọn tun ranṣẹ pe arabinrin yii ni ọjọ keji pe ko wa wi tẹnu rẹ lori bi o ṣe kọlu ọga ọlọpaa naa, nṣe lo tun mu awọn ọlọpaa obinrin mejeeji Ripẹtọ Ojola Abiola ati Queen Eguaje ti wọn ran sii lu, koda o tun ge ọkan ninu wọn jẹ pẹlu.

Ọlọpaa mu ọdọkunrin kan

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Ọga ọlọpaa lorilẹ-ede Naijiria wa ke si kọmiṣọna ọlọpaa lati ṣe iwadii si iṣẹlẹ naa lati lee gbe igbesẹ to ba ts ni ibamu pẹlu ofin.

Bakan naa lo kan sara si ọga ọlọpaa Adeyẹmọ fun iwa ọmọluabi ati ikora-ẹni-ni-ijanu to hu pẹlu bi obinrin yii ṣe n luu to lọjọ naa.

O ni eyi jẹ apẹrẹ oniruru ikọlu ti awọn ọlọpaa n dojukọ lẹnu iṣẹ wọn

Amọṣa ọga ọlọpaa patapata lorilẹ€de Naijiria ni ko si ẹnikẹni to ba tun ṣiwọ lu ọlọpaa to n ṣe iṣẹ rẹ mọ lorilẹede Naijiria ti ko ni jẹ iyan rẹ ni iṣu.

O ni ko din ni ọlọpaa mẹtadinlọgbọn tawọn eeyan bii arabinrin Afọlakẹ ti kọlu lati igba ti ajakalẹ arun COVID-19 yii ti bẹrẹ, ọpọlọpọ ninu wọn lo si ti di ero ileewosan ninu eyi ti wọn ko tii bọ di bi a ṣe n sọrọ yii.

Laarin asiko ti a n sọrọ rẹ yii naa, ọkọ ọlọpaa bii marundinlogun ni awọn eeyan kan ti bajẹ, pẹlu ileeṣẹ ọẹọpaa meji ni Katsina ati Abia ni awọn eeyan kan ti dana sun.

Òrìṣà ni ìyá mi, kìí ṣe ènìyàn, òun sì ni alátìlẹ́yìn mi - Wòlíì Àrólé

Woli arole

Oríṣun àwòrán, Wolii arole

Ilumọọka adẹrinposonu lórí ayelujara, Oluwatoyin Bayegun, tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ si Wòlíì Arole, tí ṣàlàyé pé ore-ọ̀fẹ́ àti àánú Ọlọ́run ló gbé òun sókè.

O sọ nipa irinajo rẹ láti ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì ti òun ti bẹ̀rẹ̀ awada lórí ayelujara.

Wòlíì Arole, lásìkò to ń bá BBC Yoruba sọ̀rọ̀ ṣàlàyé pé, isẹ awada sise tí gbé òun de ibi gíga, tí òun kò lérò pé òun leè de rí, tí òun ṣi tún mọ àwọn èèyàn ńlá-ńlá pẹ̀lú.

"Mo ti lọ sí ilé aarẹ Nàìjíríà, Aso Rock ni ẹẹmeji, ìyàwó Buhari gan tí fun mi ni àmì ẹyẹ rí, mo sì máa ń lọ silu oyinbo loore koore, láti ipasẹ awada yìí náà ni."

Wòlíì Arole ni "ọpọ ni kò fẹ́ kọ́kọ́ tẹ́wọ́ gba mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀, wọn ní èdè Yorùbá ni mo ń sọ àmọ́ nígbà tí kìí se àwọn ni Ọlọ́run, mo rí ọ̀nà àbáyọ."

Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìpènijà tó ti là kọjá sẹ́yìn, Wòlíì Arole ni ọjọ́ kan wà tí wọn gba òun sì ẹgbẹ́ níbi ayẹyẹ kan torí pé òun kò tíì ní òkìkí nígbà náà àmọ́ òun dúpẹ́ fún ibi tí Ọlọ́run mú òun de lónìí.

" Ẹ̀jẹ̀ mi ni Jésù, n kò sì tíì dé ibi tó ń mú mi lọ.

Mo sì ń rọ àwọn èèyàn láti mase ro ara wọn pín, tàbí mú ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọkàn wọn nitori ohun tí àwọn ènìyàn ba n sọ.

Ọlọ́run ní kẹ gbé ọkàn yín lé, torí ohun ènìyàn kọ ni ohùn Ọlọ́run."

Àkọlé fídíò, Se lootọ ni pe eniyan le ko Coronavirus lara ẹni to ti kú?

O wa ṣàlàyé pé "Ọlọ́run ran iya mi sì mi. Òrìṣà ni ìyá mi, kii se ènìyàn. Mo fẹ́ràn ìyá mi gan-an ni,

Kò sì sí Wòlíì Arole lai si ọwọ màmá mi nibẹ.

Ó mọ mi denudenu, to sì fẹ́ràn mi tọkàntọkàn, tí ọkàn mi bá sì rẹ̀wẹ̀sì, ìyá mi lo máa ń tú mi nínú."

Wòlíì Arole ni, ẹ̀bùn ni awada òun, tí ayé fi ń ko o jẹ, òun kii sì roo awada ti tẹ́lẹ̀, kí òun tó sọ síta, èyí tó máa ń jẹ ìtẹ́wọ́gbà lọdọ aráyé.

Arole ni òun kò tíì ní ìyàwó nílé, àmọ́ ẹ̀mí Ọlọ́run ni yóò dárí òun lati darí isẹ àti ìdílé òun, lásìkò ti oun bá ní ìdílé.

Woli arole

Oríṣun àwòrán, Wolii arole

"O wu mi kì ń ṣe sinima àti show tèmi, kí n sì ni studio tèmi náà,

Bẹ́ẹ̀ si ni èdè òyìnbó yọ lẹ́nu mi pẹ̀lú, bí mo ṣe leè ṣe awada ni ojúlówó èdè Yoruba náà ni awada tún dùn lẹ́nu mi ni èdè gẹ̀ẹ́sì, mo sì ni eto fún méjèèjì pẹ̀lú ni ọjọ́ iwájú."

Arole wá rọ àwọn olólùfẹ́ rẹ láti jókòó sínú ilé wọn lásìkò igbele Coronavirus yìí, kí wọn sì mú gbogbo ìmọ̀ràn àti arọwa tí ìjọba ń pa fún wọn lọ nítorí ẹ̀mí kò ní ààrọ̀.

Aworan atọnisọna

Iye awọn to ti ni arun naa lagbaye

Group 4

Jọwọ ṣe atunṣe ilana ikansi ayelujara rẹ lati ri ẹkunrẹrẹ rẹ

Orisun: Johns Hopkins University atawọn ajọ eto ilera ilu

Igba ti wọn kede iṣiro awọn to nii kẹyin 5 Oṣù Agẹmọ 2022 10:59 WAT+3

Ẹkunrẹrẹ data

Sun atẹ wa silẹ tabi oke lati ri ẹkunrẹrẹ akọsilẹ

*Iye awọn to tọwọ aisan ku ni isọri eeyan ẹgbẹrun lọna ọgọrun

Orilẹede Amẹrika 1012833 308.6 87030788
Orilẹ́ede Brazil 672033 318.4 32535923
Orilẹede India 525242 38.4 43531650
Orilẹede Russia 373595 258.8 18173480
Orilẹede Mexico 325793 255.4 6093835
Orilẹede Peru 213579 657.0 3640061
Ilu Ọba 177890 266.2 22232377
Orilẹede Italy 168604 279.6 18805756
Orilẹede Indonesia 156758 57.9 6095351
Orilẹede France 146406 218.3 30584880
Orilẹede Iran 141404 170.5 7240564
Orilẹede Germany 141397 170.1 28542484
Orilẹede Colombia 140070 278.3 6175181
Orilẹede Argentina 129109 287.3 9394326
Orilẹede Poland 116435 306.6 6016526
Orilẹede Ukraine 112459 253.4 5040518
Orilẹede Spain 108111 229.6 12818184
Orilẹede South Africa 101812 173.9 3995291
Orilẹede Turkey 99057 118.7 15180444
Orilẹede Romania 65755 339.7 2927187
Orilẹede Phillippines 60602 56.1 3709386
Orilẹede Chile 58617 309.3 4030267
Orilẹede Hungary 46647 477.5 1928125
Orilẹede Vietnam 43088 44.7 10749324
Orilẹede Canada 42001 111.7 3958155
Orilẹede Chech 40324 377.9 3936870
Orilẹede Bugaria 37260 534.1 1174216
Orilẹede Malaysia 35784 112.0 4575809
Orilẹede Ecuador 35745 205.7 913798
Orilẹede Belgium 31952 278.2 4265296
Orilẹede Japan 31328 24.8 9405007
Orilẹede Thailand 30736 44.1 4534017
Orilẹede Pakistan 30403 14.0 1539275
Orilẹede Greece 30327 283.0 3729199
Orilẹede Bangladesh 29174 17.9 1980974
Orilẹede Tunisia 28691 245.3 1052180
Orilẹede Iran 25247 64.2 2359755
Orilẹede Egypt 24723 24.6 515645
Orilẹede South Korea 24576 47.5 18413997
Orilẹede Portugal 24149 235.2 5171236
Orilẹede Netherlands 22383 129.1 8203898
Orilẹede Bolivia 21958 190.7 931955
Orilẹede Slovakia 20147 369.4 2551116
Orilẹede Austria 20068 226.1 4499570
Orilẹede Myanmar 19434 36.0 613659
Orilẹede Sweden 19124 185.9 2519199
Orilẹede Kazakhstan 19018 102.7 1396584
Orilẹede Paraguay 18994 269.6 660841
Orilẹede Guatemala 18616 112.1 921146
Orilẹede Georgia 16841 452.7 1660429
Orilẹede Sri Lanka 16522 75.8 664181
Orilẹede Serbia 16132 232.3 2033180
Orilẹede Morrocco 16120 44.2 1226246
Orilẹede Croatia 16082 395.4 1151523
Orilẹede Bosnia ati Herzegovnia 15807 478.9 379041
Orilẹede China 14633 1.0 2144566
Orilẹede Jordan 14068 139.3 1700526
Orilẹede Switzerland 13833 161.3 3759730
Orilẹede Nepal 11952 41.8 979835
Orilẹede Moldova 11567 435.2 520321
Orilẹede Israel 10984 121.3 4391275
Orilẹede Honduras 10906 111.9 427718
Orilẹede Lebanon 10469 152.7 1116798
Ilẹ Australia 10085 39.8 8291399
Orilẹede Azerbaijan 9717 96.9 793388
North Macedonia 9327 447.7 314501
Orilẹede Saudi Arabia 9211 26.9 797374
Orilẹede Lithuania 9175 329.2 1162184
Orilẹede Armenia 8629 291.7 423417
Orilẹede Cuba 8529 75.3 1106167
Orilẹede Costa Rica 8525 168.9 904934
Orilẹede Panama 8373 197.2 925254
Orilẹede Afganistan 7725 20.3 182793
Orilẹede Ethiopia 7542 6.7 489502
Orilẹede Ireland 7499 151.8 1600614
Orilẹede Uruguay 7331 211.8 957629
Orilẹede Taiwan 7025 29.5 3893643
Orilẹede Belarus 6978 73.7 982867
Orilẹede Algeria 6875 16.0 266173
Orilẹede Slovenia 6655 318.7 1041426
Orilẹede Denmark 6487 111.5 3177491
Orilẹede Libya 6430 94.9 502189
Orilẹede Latvia 5860 306.4 837182
Orilẹede Venezuela 5735 20.1 527074
Agbegbe Palestine 5662 120.8 662490
Orilẹede Kenya 5656 10.8 334551
Orilẹede Zimbabwe 5558 38.0 255726
Orilẹede Sudan 4952 11.6 62696
Orilẹede Finland 4875 88.3 1145610
Orilẹede Oman 4628 93.0 390244
Orilẹede Dominican Republic 4383 40.8 611581
Orilẹede El Salvador 4150 64.3 169646
Orilẹede Namibia 4065 163.0 169247
Orilẹede Trinida and Tobago 4013 287.7 167495
Orilẹede Zambia 4007 22.4 326259
Orilẹede Uganda 3621 8.2 167979
Orilẹede Albania 3502 122.7 282690
Orilẹede Norway 3337 62.4 1448679
Orilẹede Syria 3150 18.5 55934
Orilẹede Naijiria 3144 1.6 257637
Orilẹede Jamaica 3144 106.6 143347
Orilẹede Kosovo 3140 175.0 229841
Orilẹede Cambodia 3056 18.5 136296
Orilẹede Kyrgyzstan 2991 46.3 201101
Orilẹ́ẹede Boswana 2750 119.4 322769
Orilẹede montenegro 2729 438.6 241190
Orilẹede Malawi 2646 14.2 86600
Orilẹede Estonia 2591 195.3 580114
Orilẹede Kuwait 2555 60.7 644451
Orilẹede United Arab Emirates 2319 23.7 952960
Orilẹede Mozambique 2212 7.3 228226
Orilẹede Mongolia 2179 67.6 928981
Orilẹede Yemen 2149 7.4 11832
Orilẹede Senegal 1968 12.1 86382
Orilẹede Cameroon 1931 7.5 120068
Orilẹede Angola 1900 6.0 101320
Orilẹede Uzbekistan 1637 4.9 241196
Orilẹede New Zealand 1534 31.2 1374535
Orilẹede Bahrain 1495 91.1 631562
Orilẹede Rwanda 1460 11.6 131270
Orilẹede Ghana 1452 4.8 166546
Orilẹede Singapore 1419 24.9 1473180
Orilẹede Swaziland 1416 123.3 73148
Orilẹede Madagascar 1401 5.2 65787
Orilẹede Congo 1375 1.6 91393
Orilẹede Suriname 1369 235.5 80864
Orilẹede Somalia 1361 8.8 26803
Orilẹede Guyana 1256 160.5 67657
Orilẹede Luxembourg 1094 176.5 265323
Orilẹede Cyprus 1075 89.7 515596
Orilẹede Mauritius 1004 79.3 231036
Orilẹede Mauritania 984 21.7 60368
Orilẹede Martinique 965 257.0 195912
Orilẹede Guadeloupe 955 238.7 168714
Orilẹede Fiji 866 97.3 65889
Orilẹede Tanzania 841 1.4 35768
Orilẹede Haiti 837 7.4 31677
Erekusu Bahamas 820 210.5 36101
Erekusu Reunion Island 812 91.3 422769
Orilẹede Cote d‘ivoire 805 3.1 83679
Orilẹede Laos 757 10.6 210313
Orilẹede Malta 748 148.8 105407
Orilẹede Mali 737 3.7 31176
Orilẹede Lesotho 699 32.9 33938
Orilẹede Belize 680 174.2 64371
Orilẹede Quatar 679 24.0 385163
Orilẹede Papua New Guinea 662 7.5 44728
Agbegbe French Polynesia 649 232.4 73386
Erekusu Barbados 477 166.2 84919
Orilẹede Guinea 443 3.5 37123
Erekusu Cape Verde 405 73.6 61105
Agbegbe French Guiana 401 137.9 86911
Orilẹede Burkina Faso 387 1.9 21044
Orilẹede Olominira Congo 385 7.2 24128
Erekusu Saint Lucia 383 209.5 27094
Orilẹede Gambia 365 15.5 12002
Orilẹede New Caledonia 313 108.8 64337
Orilẹede Niger 310 1.3 9031
Orilẹede Maldives 306 57.6 182720
Orilẹede Gabon 305 14.0 47939
Orilẹede Liberia 294 6.0 7497
Curaçao 278 176.5 44545
Orilẹede Togo 275 3.4 37482
Orilẹede Nicaragua 242 3.7 14690
Orilẹede Grenada 232 207.1 18376
Orilẹede Brunei 225 51.9 167669
Orilẹede Aruba 222 208.8 41000
Orilẹede Chad 193 1.2 7426
Orilẹede Djibouti 189 19.4 15690
Orilẹede Mayotte 187 70.3 37958
Orilẹede Equatorial Guinea 183 13.5 16114
Orilẹede Iceland 179 49.5 195259
Erekusu Channel 179 103.9 80990
Orilẹede Guinea Bissau 171 8.9 8369
Orilẹede Seychelles 167 171.1 44847
Orilẹede Benin 163 1.4 27216
Orilẹede Comoros 160 18.8 8161
Orilẹede Andorra 153 198.3 44177
Erekusu Solomon Islands 153 22.8 21544
Orilẹede Antigua ati Barmuda 141 145.2 8665
Erekusu Bermuda 140 219.0 16162
Orilẹede South Sudan 138 1.2 17722
Orilẹede Timor-Laste 133 10.3 22959
Orilẹede ajikistan 125 1.3 17786
Orilẹede Sierra Leone 125 1.6 7704
Orilẹede San Marino 115 339.6 18236
Agbegbe St Vincent and the Grenadines 114 103.1 9058
Orilẹede Central African Republic 113 2.4 14649
Isle of Man 108 127.7 36463
Orilẹede Gilbraltar 104 308.6 19633
Orilẹede Eritrea 103 2.9 9805
Erekusu Saint Martin 87 213.6 10601
Orilẹede Liechtenstein 85 223.6 17935
Orilẹede Sao Tomẹ́ and Principe 74 34.4 6064
Orilẹede Dominican 68 94.7 14852
Erekusu Saint Martin ( Agbegbe ti France) 63 165.8 10952
Erekusu Virgin Island tilẹ Gẹẹsi 63 209.8 6941
Orilẹede Monaco 59 151.4 13100
Erekusu Kitts and Nevis 43 81.4 6157
Orilẹede Burundi 38 0.3 42731
Bonaire, Sint Eustatius and Saba 37 142.4 10405
Erekusu Turks and Caicos Island 36 94.3 6219
Erekusu Cayman Island 29 44.7 27594
Orilẹede Samoa 29 14.7 14995
Erekusu Faroe Island 28 57.5 34658
Orilẹede Bhutan 21 2.8 59824
Orilẹede Geenlande 21 37.3 11971
Orilẹede Vanuatu 14 4.7 11389
Orilẹede Kiribati 13 11.1 3236
Ọkọ oju omi Diamond Cruise 13 712
Orilẹede Tonga 12 11.5 12301
Orilẹede Anguilla 9 60.5 3476
Orilẹede Montserrat 8 160.3 1020
Wallis and Futuna Islands 7 61.2 454
Orilẹede Palau 6 33.3 5237
Saint Barthélemy 6 60.9 4697
Ọkọ oju omi Zaandam 2 9
Erekusu Cooks Island 1 5.7 5774
Saint Pierre and Miquelon 1 17.2 2779
Erekusu Falkland Island 0 0.0 1815
Orilẹede Micronesia 0 0.0 38
Ilu Vatican 0 0.0 29
Erekusu Marshall islands 0 0.0 18
Ilẹ antarctica 0 11
Oke Saint Helena 0 0.0 4

Jọwọ ṣe atunṣe ilana ikansi ayelujara rẹ lati ri ẹkunrẹrẹ rẹ

Akọsile imọ yii, da lori akojọpọ iṣẹ iwadi ni Fasisti Johns Hopkins, o si le ma ṣe afihan awọn akọsilẹ iroyin to ba igba mu lati orilẹede kankan.

** Àwọn iyé akọsilẹ̀ to ti wà fún àwọn ti o ṣẹ́ṣẹ̀ ni ààrun náà jẹ́ àkójọpọ̀ ọjọ́ mẹ́ta. Nítori àwọn àtúgbẹ́yẹ̀wò, o níra láti ṣe àkójọpọ fún àwọn ọkọ́ naa

Orisun: Johns Hopkins University atawọn ajọ eto ilera ilu

Iye akọsilẹ to waye gbẹyin 5 Oṣù Agẹmọ 2022 10:59 WAT+3

Gbenga Adeboye: Ó tẹ́ bàbá mi lọ́rùn pé ká mu gàárì nílé ju kí ebi pa ará ìta lọ - Ọmọ Gbenga Adeboye

Àkọlé fídíò, Gbenga Adeboye: Ó tẹ́ bàbá mi lọ́rùn pé ká mu gàárì nílé ju kí ebi pa ará ìta lọ -

Oluwadamilola Adeboye, tíì ṣe ọmọbìnrin gbajugbaja adẹrinposonu nnì, Gbenga Adeboye, tí sọ àwọn ìrírí tó sì rántí nípa bàbá rẹ̀ tó ti di olóògbé.

Bẹẹ bá gbàgbé, Gbenga Adeboye lo jáde láyé ni ọgbọnjọ oṣù kẹrin ọdún 2003, èyí tó pé ọdún mẹtadinlogun lonii Ọjọ́bọ.

Nígbà tó ń bá BBC Yoruba sọ̀rọ̀ láti sàmì ayajọ ìrántí ikú olóògbé náà, Oluwadamilola ni bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun kéré pupọ nígbà tí bàbá òun kú, àmọ́ òun leè ṣe àpèjúwe rẹ bíi ẹni tó gbé aye ṣe rere.

Oluwadamilola ni òun kò mọ ibi tí bàbá òun ti rí ẹ̀bùn tó ni àmọ́ ó fikùn pé, àwọn ẹ̀bùn rẹ náà kasiara, tó sì tún ya ní lẹ́nu pupọ.

O ṣàlàyé pé nígbà tí bàbá òun wà láyé, ojoojumọ ni ile àwọn máa ń kùn, tí àwọn èèyàn máa ń wa, táwọn yóò sì gba àlejò, tí bàbá òun yóò sì máa ń ṣe awada pẹlu wọn, tí inú àwọn èèyàn yóò sì máa dùn, tí

wọn kò sì ní fẹ́ kúrò nínú ilé àwọn.

"Mo sì lee rántí pé Baba mi jẹ́ èèyàn rere, kò si ẹni ti kii se oore fún, kò si mọ bá ṣe ń kọ láti ṣe nkan fún èèyàn, tí onitọun bá nílò iranlọwọ."

Nígbà miran ti bàbà mi bá dé sílè láti ibi tó ti lọ dá ẹrin posonu, tí a kò si ni oúnjẹ nílé, bí màmá mi bá béèrè pé owó tó mú bọ dà, yóò dáhùn pé òun ti pín owó náà fún àwọn tí ebi ń pá, tí yóò sì ní ká lọ mu

gàárì, òun yóò fún wa lowo lọ́la láti fi ṣe irẹsi."

Àkọlé fídíò, 'Mo ni baba isalẹ'

Ọmọbìnrin Gbenga Adeboye náà fikùn pé, Baba òun ni ifẹ gbogbo ènìyàn bíi ọmọ àti àbúrò rẹ ni, ó sì tẹ bàbá òun lọrun pé ki awọn ẹbi rẹ mu gàárì kí àwọn ará ìta leè rí oúnjẹ jẹ, tàbí rí owó fún àwọn èèyàn.

Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa ohun tí àwọn ẹbí fẹ́ máa fi ṣe irántí Gbenga Adeboye, Oluwadamilola ni "èmi àti màmá pẹ̀lú àwọn àbúrò mi ti pinnu láti máa ṣe atilẹyin fún àwọn osere tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dìde nilẹ láti ìpilẹ̀ṣẹ̀, ní

kété tí ajakalẹ àrùn Coronavirus bá ti tan."

O fikùn pé, àwọn yóò ṣe iranwọ fún àwọn osere tíátà lobinrin àti àwọn aláìní pẹ̀lú nítorí ohun tó máa ń mú inú bàbá òun dùn nìyẹn, èyí tíì ṣe fífún àwọn aláìní ni oúnjẹ.Bákan náà lo fikun pé ní ọjọ́ iwájú, tí àwọn bá tún ní erongba miran ti àwọn fẹ́ ṣe fún ìrántí Adeboye, àwọn yóò kéte síta.

Coronavirus
Coronavirus

Lockdown: Ká ní kò sí kónílé ó gbélé, èmi àti Chioma ì bá ti dàgboro rú- Davido

Chioma, afẹsọna Davido

Oríṣun àwòrán, davido/instagram

Ilumọọka olorin takasufe Davido ti kọ iwe ifẹ kan ṣọwọ si afẹsọna rẹ ati ọmọ wọn ni ọjọ ibi Chioma to n waye lọjọbọ

Eyi wa loju opo Instagram rẹ.

Mo ki obinrin to lagbara kulọ lara awọn ti mo mọ ku ọjọ ibi. Ka ni ko si ofin konile o gbele ni, awa mejeeji o ba ti jaye ori wa daada kaakiri igboro loni

Iyawo mi tootọ, ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ yoo larinrin bi iwọ pẹlu ti ṣe mu ọpọlọpọ ayọ wọ inu aye mi.

O ti le ni ọdun meji bayii ti Davido ati Chioma ti bẹrẹ irinajo ifẹ wọn ti Eleduwa si ti fi ọmọkunrin kan tawọn lọrẹ.

Laipẹ yii ni Chioma bọ lọwọ arun Coronavirus lẹyin ọpọlọpọ ọjọ ti aisan naa fi daa wolẹ.

Àkọlé fídíò, Ẹ̀mí kan náà ló n darí ìrìnàjò wa táa fi jọ kọ́lé papọ̀- Ìbejì
Coronavirus
Coronavirus

Coronavirus in Osun: Iṣẹ́ labiyamọ ń ṣe o, Davido pariwo síta lórí bó ṣe ń tọ́jú ọmọ tí Chioma fi sílẹ̀ fún

davido ati ọmọ rẹ

Oríṣun àwòrán, davido

Gbajugbaja akọrin takasufe ni, David Adeleke ti ọpọlọpọ mọ si Davido ti pariwo sita pe nnkan ko rẹrin lori titọju ọmọ ti oun ti iyawo rẹ Chioma bi fun latigba ti iya rẹ ti wa ni igbele iyasọtọ.

Chioma, iyawo Davido ko arun Coronavirus eleyi ti ọkọ rẹ, Davido kede faye ni ọsẹ to kọja.

Ninu ọrọ kan to fi sita loju opo twitter rẹ Davido lọgun pe iṣẹ l'abiyamọ n ṣe.

Lẹyin ti ayẹwo fihan pe Chioma ti ko arun Coronavirus, igba meji ọtọọtọ ni Davido ni oun ti ṣe ayẹwo lati lee mọ boya oun ni arun naa tabi oun ko ni.

Àwọn olùgbé ìlúu Abidjan ló kò àrùn Coronavirus wọ Ọ̀ṣun-Gómìnà Oyètọ́lá

Àkọlé fídíò, Coronavirus in Nigeria: Gómìna Oyetola ní àwọn àbọ̀dé orílẹ̀èdè Côte d'Ivoire ló ń

Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alaaji Adegboyega Oyetọla ti ke gbajare sita pe awọn abọde lati orilẹede Côte d'Ivoire ni wọn jẹ ki ajakalẹ arun Coronavirus tubọ gogo sii ni ipinlẹ naa.

Ninu ọrọ to ba BBC News Yoruba sọ lori ẹrọ ibanisọrọ lẹyin ti ajọ to n gbogun ti ajakalẹ arun tun kede eeyan mẹsan miran pẹlu arun Korona ni ipinlẹ Ọṣun lọjọru, Gomina Oyetọla ṣalaye pe arun Korona ki ba ti burẹkẹ to bayii kani ijọba apapọ tete ti gbogbo ẹnuibode ni ki wọn si paṣẹ konileogbele fun gbogbo ọmọ orilẹede Naijiria.

Gomina Oyetọla ṣalaye siwaju sii pe, awọn ọmọ ipinlẹ naa ti wọn n ti orilẹede Côte d'Ivoire bọ wa sile ni wọn ko arun naa dani to fi di pe o tubọ peleke sii nipinlẹ naa.

O wa rọ awsn eeyan ipinlẹ Ọṣun lati fidimọle gẹgẹ bi aṣẹ ti ijọba pa lati lee wagbo dẹkun si wahala yii.

Bakan naa ni o fi to wa leti pe lọna ati lee dẹkun ọwọja ebi ati inira lasiko aṣẹ konileogbele naa, ijọba oun ti gbe awọn igbesẹ ti yoo bu omi tu araalu lara bii sisanwo oṣu fun awọn oṣiṣẹ ki wọn to gbe aṣẹ naa kalẹ ati idasilẹ igbims majẹobajẹ kan lori ọna ati gbogun ti arun naa ati lati mu irọrun ba araalu lasiko ti wọn ba fi n baa wọ iyaaja.

Ẹkunrẹrẹ wa ninu ohun ti a ka silẹ loke yii.

Afikun nipa aarun Coronavirus

Coronavirus in Nigeria: Davido ní àyẹ̀wò kejì fún àrùn Coronavirus fihàn pé ṣáká lara le

Davido ati iyawo, Chioma

Oríṣun àwòrán, Davido/instagram

Gbajugbaja akọrin takasufe, Divid Adeleke ti ọpọ eeyan mọ si Davido tun ti wẹ yan kainkain lọwọ arun coronavirus.

Ọpọ ẹnu lo ti n kun Davido lẹyin ti iroyin jade pe ọpọ awọn eeyan to sun mọọ lo ti n ni arun yi lara.

Ni ọjọ diẹ sẹyin ni Davido funrarẹ gbe iroyin jade pe iyawo oun, Chioma ti ko arun Coronavirus, bakan naa si ni gomina Seyi Makinde pẹlu kede pe oun pẹlu ti ni arun naa lẹyin ọjọ diẹ to gbalejo Davido ni ile ijọba nilu Ibadan.

Ninu atẹjade kan to fi sita loju opo twitter rẹ ni ọsan ọjọ Ọjọru, Davido ni oun ti tun ayẹwo arun Coronavirus ṣe o, ṣaka bayii si ni ara oun ya.

Afikun nipa aarun Coronavirus

Coronavirus in Nigeria: Wo àwọn ìrìnàjò tí gómìnà Makinde rìn kí èsì àyẹ̀wò rẹ̀ tó jáde

mAKINDE ATI sANWOOLU N KI ARA WọN NIBI IPADE KAN LọDUN 2019

Oríṣun àwòrán, SEYI MAKINDE

Gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọẹrọ Ṣeyi Makinde kede ni aṣalẹ ọjọ Aje pe oun ti ko arun Coronavirus ti o n ja kale-ka'ko bayii.

O fi si oju opo twitter rẹ pe esi ayẹwo oun ti de ko si si ẹja n bakan kankan lori rẹ nitori ẹja lo ba de.

Lẹyin eyi ni o ṣalaye pe gbogbo awọn to ti ni nnkan n ba oun ṣe laarin asiko ti oun fi lọ sibi ipade igbimọ ọrọ aje orilẹede Naijiria si ọjọ ti oun bẹrẹ igbele ni wọn ti n wa; koda iroyin kan tilẹ ss pe gbogbo awọn to baa da nnkan pọ laarin asiko naa, paapaa awọn kọmiṣọna atawọn amugbalẹgbẹ rẹ gbogbo ni wọn ti wa ni igbele bayii lati lee mọ boya awọn naa ko abi rara.

mAKINDE N BA AWọN EEYAN KAN SọRọ

Oríṣun àwòrán, SEYI MAKINDE

Nibayii, BBC News Yoruba ṣe atupalẹ bi irinajo Gomina Seyi Makinde ṣe lọ laarin akoko naa ati awọn eeyan to ṣeeṣe ki wọn ti ko arun yii lati ara rẹ.

Ẹ maa gbagbe pe eyi ko tumọ si pe gbogbo awọn eeyan to wa nibi eto wọnyii lo ti koo, ṣugbọn iwadi ati ayẹwo to gbọngbọn nikan lo lee fi idi eyi mulẹ.

Fun apẹrẹ, gomina Makinde ṣalaye ninu atẹjade to fi sita pe asiko kan naa ni esi ayẹwo oun ati ti akọwe ijọba ipinlẹ naa, arabinrin Olubamiwo Adeosun de. Esi ti gomina lo jasi bẹẹni ti ti akọwe ijọba ipinlẹ naa si ja si bẹẹkọ.

Idi ti awọn onimọ maa fi n ṣe ato irinajo ẹni to ba ni arun yii ni lati mọ ibi ti wọn lee wa awọn to lee ti koo lati ara wọn si.