Coronavirus: Ọmọ márùn ún ni mo ní, ṣùgbọ́n kò sí oúnjẹ fún wa lásìkò ìgbélé yìí -Olùgbé ìlú Eko
Awọn olugbe ipinlẹ Eko ti rawọ ẹbẹ si ijọba ipinlẹ naa lati wa nkan ṣe si ọrọ igbele to wa lode nitori ebi.
Lara awọn to ba BBC Yorua sọrọ ni nkan ko rọgbọ fun wọn lati igba ti igbele naa ti bẹrẹ.
Awọn eeyan naa ni wọn ko ri ounjẹ ati owo ti ijọba fi ranṣẹ.
Gbogbo bi ọrọ ọhun ṣe jẹ wa ninu fido yii.
- Bukky Wright ṣ'ọjọ́ ìbí, Lizzy Anjorin f'orin bọnu, Femi Adebayo sọ ẹran àgbò rẹ̀ lórúkọ tuntun
- Mohammed, ọmọ Abubakar Atiku sọ̀rọ̀ lórí àrùn Coronavirus tó ń báa finra
- Kí ló pa bàbá Adeboye, bàbá Davido àti Ọ̀ọ̀ni Ifẹ̀ pọ̀ lásìkò ìgbélé l'Ọ́ṣun?
- Ìròyìn ayọ̀! èèyàn mẹ́rin míràn móríbọ́ lọ́wọ́ Coronavirus l'Eko