Coronavirus in Nigeria: Ẹ wo àǹfààní tó wà nínú àrùn Coronavirus

Àkọlé fídíò, Coronavirus in Nigeria: Ẹ wo àǹfààní tó wà nínú àrùn Coronavirus

Awọn onimọ ti ṣe iwadii pataki to fi ọna lati kapa Coronavirus lede.

Eyi ko ṣẹyin bi awọn eniyan ilẹ South Korea ṣe ti ni awọn eniyan perete to ti ni arun naa.

Wọn fikun un pe ọna abayọ n bọ laipẹ llati koju arun Coronavirus.

Bẹẹ ni wọn ke si awọn eniyan lati sa ipa wọn lati fọ ọwọ wọn ni igba de igba.

Bakan naa ni wọn sọ wi pe yiyago fun ara ẹni ṣe pataki ni asiko yii.

Ẹ wo ẹkunrẹrẹ fidio yii fun igbese ti awọn eniyan n gbe lati kapa arun Coronavirus.