Ooni of Ife: Àwòrán ọmọ mi kọ́ lẹ ń rí lórí ayélujára o, ọmọ ọ mi ń ṣètùtù lọ́wọ́- Ọba Adeyeye Ogunwusi

Oríṣun àwòrán, @ooni
Èyí ni ohun tí Ọọ̀ni sọ nípa Àrẹ̀mọ rẹ àti ètùtù tó ń ṣe lọ́wọ́
Laipẹ yii ni awọn eeyan kan n gbe fọto kan kiri lori ayelujara tiwọn kan ni o jẹ ti Arẹmọ tuntun ti Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi ṣẹṣẹ bi
Amọṣa, Kabiyesi Ọọni ti pariwo sita pe aworan naa kii ṣe ti Arẹmọ oun.
- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ṣàfihàn ojú àwọn afurasí tó se ẹran ara ọlọ́pàá jẹ ní Ibadan
- Wo ọ̀nà tí ọrọ̀ ajé Naijiria tó dẹnu kọlẹ̀ gba kàn ọ
- Mílíọ́nù mẹ́wàá Náírà ni ilé ẹjọ́ ni kí Kábíyèsí san gẹ́gẹ́ bí owó ìtaran ilẹ̀ tí ó gbà lọ́nà àìtọ́
- Kíni àjọ ọlọ́pàá ń ṣe lórí bí agbófinró ṣe ń ṣèèṣì pànìyan lójoojúmọ́?
- Ilé aṣòfin orílẹ̀-èdè UK ti faramọ́ fífí ìyà jẹ àwọn adarí Naijiria tọ lọ́wọ́ nínú rògbòdìyàn ENDSARS
Ninu ọrọ kan ti o jade lati ile Oodua ti ṣe Aafin Ọọni nilu Ile Ife, ni wọn ti ni aworan Arẹmọ Ọọni ko tii jade sọwọ ẹnikẹni.
Koda, wọn fidiẹ mulẹ pe nigbakugba ti Kabiyesi yoo ba fẹ ki agbaye ri oju Arẹmọ, oun funrarẹ ni yoo fi aworan naa sita gẹgẹ bi i baba ọmọ.
- Kíni àjọ ọlọ́pàá ń ṣe lórí bí agbófinró ṣe ń ṣèèṣì pànìyan lójoojúmọ́?
- Iṣu ata yáan yàan! Iṣẹ́ fẹ́ bọ́ lọ́wọ́ ọlọ́pàá tó gba N100k lọ́wọ́ awakọ̀ tó gba"One way" l'Eko
- Ìjọba Naijiria faraya nínú lẹ́tà tó kọ sí CNN lórí ìwádìí rẹ̀ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki Toll Gate
- Omotara pàdánù isẹ́ olówó ńlá nítorí ó fi ọtí ẹlẹ́rìndòdò sódà lá ọmọ alágbe lójú
- Jemila dáná sún ilé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ àti ọ̀rẹ́bìnrin tó bá nílé
Atẹjade naa tun jẹ ko di mimọ pe, awọn etutu gbogbo to yẹ n lọ lọwọ fun Arẹmọ gẹgẹ bi iṣẹṣe ṣe laa kalẹ,
Ati pe, o si di igba ti wọn ba pari awọn etutu wọnyi ki ẹnikẹni to lee ri Arẹmọ Ọọni naa.
"Baba rẹ, Aroke Ooduduwa, Olofin Adimula, Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi, Ojaja II, Ooni Ife to ni gbogbo aṣẹ lati fi oju ọmọ naa han fun araye
ko tii ṣe bẹẹ nitori pe awọn etutu gbogbo to yẹ lati fi ki Arẹmọ kaabọ ṣin lọ lọwọ".
- Wo ohun mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ tí o bá fẹ́ lọ fún ìsinmi lẹ́yìn Covid 19
- Wo bí o ṣe lè ṣe eré ìdárayá tí yóò fún ọ ní adùn àti okun fún ìbálòpọ̀
- DSS ti fi ẹ̀sọ́ àbò abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asofin tó pa fẹ́ndọ̀ l'Abuja sátìmọ́lé
- Wọ́n ti rí òkú Alága ẹgbẹ́ APC ní Nasarawa tí àwọn agbébọn jí gbé lọ́jọ́ Satide
















