Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn méji tó jẹ ẹran ara ọlọ́pàá tí wọ́n pa n'Ibadan

Oríṣun àwòrán, others
Ẹran ara ọlọ́pàá di èkìrí ẹran súyà, wo àwọn tó jẹ́ níbẹ́.
Awọn ọlọpaa ni ipinlẹ Oyo ti mu awon meji ti wọn ni wọn fẹsun kan pe wọn n sunẹran ọlọpaa jẹ lasiko iwọde #EndSARS to kọja.
Alukoro ileṣẹ ọlọpaa ni ipinlẹ Ọyọ, SO Olugbenga Fadeyi ti salaye fawọn akọroyin pe lootọ ni o.
- SERAP ké sí ìjọ̀ba láti mú àdínkù bá owó ìná ìṣèjoba
- DSS ti fi ẹ̀sọ́ àbò abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asofin tó pa fẹ́ndọ̀ l'Abuja sátìmọ́lé
- Wọ́n ti rí òkú Alága ẹgbẹ́ APC ní Nasarawa tí àwọn agbébọn jí gbé lọ́jọ́ Satide
- Òtítọ́ làwọn sọ́jà gbé ìbọn tó lọ́ta gidi nínú lọ sí Lekki Toll Gate lásìkò ìwọ́de EndSARS- Ọ̀gágun Taiwo
Awọn afunrasi mejeeji naa oloyun ọmọ ọdun mẹrinlelọgbọn kan pẹlu arakunrin ẹni ọdun mẹtalelogoji ọhun ti n turabayii nileeṣẹ ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ nilu Abuja.
Alaboyun naa la gbo pe o jẹ ẹran ara ọlopaa kan ṣugbọn to ni iọ ni wọn pa mọ oun. Amọṣa, ọgangan ibi ti iṣẹlẹ naa ti waye ni wọn ti mu.
O ni arakunrin ẹni ọdun mẹtalelogoji naa lo fun oun pe ki oun fi si ipamọ.
Bi o tilẹ jẹ pe arakunrin naa ko sẹ pe oun ko si pẹlu awọn janduku miran nibi ti iṣẹlẹ naa ti waye.
Ṣugbọn arabinrin aboyun naa lo funra rẹ bu ekiri ẹran ati pe aṣọ inuwọ lasan lo kan beere lowo oun lati fi yi wọn pamọ.

Oríṣun àwòrán, others
Awọn Ọlọpaa ti wọn sọ ara wọn di ẹran ijẹ naa wa lara awọn ọlọpaa ti wọn da sita lati lọ pana wahala iwọde #EndSARS.
End Sars yii to waye lọjọ kejilelogun, oṣu kẹwaa, ọdun 2020, nbẹ ni wọn ti kagbako iku gbigbona naa




















