End SARS, End SWAT: Ó pé mi bí SARS kò ṣe sọ mí dolówọ́- Fulani Kwajafa
Òfin àkọ́kọ́ ti SARS ti mo dá sílẹ̀ ni pé wọn kò gbọdọ̀ yìnbọn fún ẹnikẹ́ni- Fulani Kwajafa
Fulani Kwajafa to jẹ kọmiṣọnna ọlọpaa ti aarẹ Buhari paṣẹ fun pe ko da SARS silẹ lọdun 1884 gba BBC lalejo, o sọrọ ilẹ kun lori ọrọ SARS.
Fulani ni Ojukokoro ati ainitẹlọrun awọn ọga SARS ati awọn agbofinro SARS lo ba SARS de ibi to wa yii.Gbọ́ ìtàn bí ikọ̀ SARS ṣe dà bó ṣe dà láti ẹnu Ọ̀gá ọlọ́pàá tó dá SARS sílẹ̀
O sọ awọn iyatọ to wa ninu SARS ti oun da silẹ ati eyi to wa nigboro bayii.
- Irọ́ ni pé wọ́n hú òkú Kolawole Gold lórí pẹpẹ ìjọ ọkọ mi- Bisola aya Sotitobire
- Iṣẹ́ Oníbúrẹ́dì ní mo kọ́, ìfẹ́ àṣà Yorùbá ló sún mi dé ìdí ẹ̀ṣà pípé tí mo fi là- Ajobiewe
- Wo àwọn ojúṣe àti èèwọ̀ fún ikọ̀ ọlọ́pàá SWAT tó gba iṣẹ́ lọ́wọ́ SARS
- Mọ̀ nípa iPhone 12, fóònù ológo 5G tí kìí lo "Charger” tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde
Fulani Kwajafa ṣalaye fun BBC pe lasiko ti oun, ko si ifiyajẹni lọna aitọ ti awọn ọdọ n ja lodi si bayii.
O ni nitootọ ni oun ni ki awọn SARS naa ni igbooya lati koju ẹnikẹni ṣugbọn awọn kii rin kaakiri igboro rara.
Iwadii ọgbọn atinuda ni awọn n lo nigba naa lai lo ibọn fi ṣe ẹnikẹni leṣe.
- Pásítọ̀ Enoch Adeboye darapọ̀ mọ̀ #ENDSARS, ó fún ìjọba Nàìjíríà ní ìmọ̀ràn ọ̀nà àbáyọ
- Kìí ṣe gbogbo ohun tí dókìtà ni kí n má jẹ torí àìsàn jẹjẹrẹ ni mo tẹ̀lé- Soyinka
- Mi ò mọ̀ nípa àwọn tọ́ọ̀gì tó da ìwọ́de EndSARS Alausa rú, mo ṣì wà lẹ́yìn yín digbí! - Sanwoolu
- Àṣé àṣírí wà nínú Hijabu tí Aisha Yesufu ń wọ̀ lọ ìwọ́de
- Kí ló ń ṣẹlẹ̀ láàfin Oyo táwọn èèyàn fi ń ki Alaafin ní mẹ́sàn án mẹ́wàá?
O sọrọ ilẹ kun lori ohun to ti ṣẹlẹ ninu SARS lẹyin ti oun fẹyin ri lọdun 1989.
Fulani sọ pe igbogun ti awọn adigunjale lati Adeniji Adele ni ipinlẹ Eko to jẹ olu ilu Naijiria nigba naa wa lara iṣẹ akanṣe to da SARS silẹ.
O sọ nipa idanilẹkọ oriṣiriṣi ti wọn ṣe ki awọn eeyan to di SARS ati paapaa ofin alakalẹ iwa ọmọluwabi ti wọn fi kọ awọn agbofinro to darapọ mọ SARS nigba naa.
Fulani sọrọ lori SWAT tuntun ti wọn yan pe SARS ko sọ ohun di ọlọrọ rara ṣugbọn o tẹ oun lọrun lati ni orukọ rere ju owo lọ.
O ni ọna lati ṣe aṣeyọri SWAT wa lọwọ irufẹ awọn ti ijọba ba gba sibẹ ati Adari tuntun ti wọn ba yan fun SWAT.
- Ìjọba kéde ọjọ́ ìwọlé àwọn àgùnbánirọ̀ sí ìpàgọ́ lẹ́yìn Covid 19- Sunday Dare
- Gbọ́ ìtàn bí ikọ̀ SARS ṣe dà bó ṣe dà láti ẹnu Ọ̀gá ọlọ́pàá tó dá SARS sílẹ̀
- Ìyá gómìnà Seyi Makinde dágbére fáyé lẹ́ni ọdún 81
- Àjọ elétò ìdìbò kéde ọjọ́ tí ìdìbò aàrẹ Nàìjíríà 2023 yóò wáyé
- 'Garri ṣíṣe kò rọrùn fún àwa obìnrin'

