Sotitobire: Ọkọ mi kò mọ̀ Jegede PDP rí, kódà kò fa ẹnikẹ́ni kalẹ̀ dípò Akeredolu- Bisola ìyàwó Alfa Sotitobire
Lati igba ti wọn ti gbe Ọkọ mi ni ọlọpaa ko ti wa ọmọ mọ- Bisola aya Wolii Sotitobirẹ
Idajọ buruku ni wọn da fun ọkọ mi ni ariwo ti Arabinrin Bisola Alfa to jẹ iyawo Wolii sotitobire n pa bayii.
O ni aṣiri ikọkọ wa lori idajọ naa ti ko han si ọpọ eeyan.
Aya wolii ṣalaye lẹkunrẹrẹ fun BBC Yoruba lori ohun to ṣẹlẹ gangan ati igbesẹ ti ọkọ rẹ gbe.
- Wo ọjọ́ tí wòlíì Sotitobire yóò gba ìdájọ́
- Ìdájọ́ òdòdò ló fẹsẹ̀ múlẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ Pásítọ̀ Sotitobire - Agbẹjọ́rò fún ìjọba
- Akure:Àwọn ọ̀dọ́ ilu dáná sun ilé ìjọsìn Sotitobire
- Iléẹjọ́ gíga Akure kọ̀ láti gba onídùróó olórí ìjọ Sotitobire
- Ejò lọ́wọ́ nínú lórí ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n gbére tí wọ́n dá fún Wòlíì Sotitobire, àwọn ọmọ ìjọ rẹ̀ yarí
- Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tó ní òun ló jí ọmọ gbé láti parọ́ mọ́ pásítọ̀ ìjọ Sotitobire
Bisola alfa sọ bi Woli se sanwo ikede ni gbogbo radio kaakiri ipinlẹ Ondo lati fi ṣawari ọmọ to sọnu, iyẹn Kolawole Gold.
O sọ irinajo ọkọ rẹ ni ọgba DSS ati ohun ti oju wọn ri to fun BBC Yoruba.
- Pásítọ̀ ìjọ Sotitobire padà yọjú sílé ẹjọ́ lónìí, àbọ̀o rèé...
- Wo ìdí tí Tẹni, ọ̀dọ́mọdé olórin obìnrin kìí fi ń ṣí ìhòhò rẹ silẹ̀
- Wo ìgbà mẹ́rin tí ìjọba ti tú ikọ̀ ọlọ́pàá SARS ká sẹ̀yín ṣùgbọ́n....
- 'Mo jíṣẹ́ ẹ rán mi'! Sanwo-olu gbé ìwé ẹ̀dùn ọkàn olùwọ́de ENDSARS lé Buhari lọ́wọ́
- Ẹ lo ìfẹ̀họ̀núhàn #EndSARS lati fí tún gbogbo ohun tó bàjẹ́ ṣe ní Naijiria- Pásítọ̀ Sam Adeyemi
Bisola Alfa ni irọ oriṣiriṣi ni wọn pa mọ ọkọ ohun ati pe wolii kii ṣe oloselu.
Nitori ki BBC Yoruba ma baa jẹ agbẹjọ ẹni kan da to jẹ agba oṣika ni wọn ṣe kan si aya Wolii naa ko sọ iha ti ẹbi wọn lori idajọ naa.
Ki Olorun ṣawari Kolawole Gold to sọnu ni adura BBC.
- Mo fẹ́ ìdájọ́ òdodo lórí ikú tó pa ọmọ mi- Baba ọmọ ti SARS pa
- Ẹfunsetan Aniwura, ọmọ Ẹ̀gbá tó di akíkanjú obìnrin nílẹ̀ Ibadan
- Iṣẹ́ Oníbúrẹ́dì ní mo kọ́, ìfẹ́ àṣà Yorùbá ló sún mi dé ìdí ẹ̀ṣà pípé tí mo fi là- Ajobiewe
- Ìya Emma oní POS ṣẹ̀ṣẹ̀ rékọjá lọ síbí ilé yẹn ni àtọmọdé, ó sì wó pa wọ́n - Láńlọọ̀dù Obalende
