INEC, 2023 election: Àjọ eleto ìdìbò kéde ọjọ́ tí ìdìbò ààrẹ Nàìjíríà 2023 yóò wáyé

Oríṣun àwòrán, @INEC
Ajọ eleto idibo orileede Naijiria ti kede ọjọ ti idibo aarẹ Naijiria yoo waye lọdun 2023.
Alaga ajọ naa Ọjọgbọn Mahmood Yakubu lo kede ọrọ yi lỌjọbọ ni olu ilẹ naa Abuja.
Mahmood ni ibo aarẹ yoo waye ni ọjọ Kejidinlogun, oṣù Keji, ọdun 2023.
Lasiko ti wọn ṣe ifilolẹ igbimọ ile aṣojuṣofin lori agbeyewo iwe ofin Naijiria, Mahmood kesi awọn aṣofin ọhun lati yara ṣiṣẹ yi ki idibo to wọle.
- Wo àwọn ojúṣe àti èèwọ̀ fún ikọ̀ ọlọ́pàá SWAT tó gba iṣẹ́ lọ́wọ́ SARS
- Pásítọ̀ Enoch Adeboye darapọ̀ mọ̀ #ENDSARS, ó fún ìjọba Nàìjíríà ní ìmọ̀ràn ọ̀nà àbáyọ
- Mọ̀ nípa iPhone 12, fóònù ológo 5G tí kìí lo "Charger” tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde
- Ẹ̀yin olùwọ́de, ẹ lọ kọwọ́ ọmọ yín bọṣọ, bí bẹ́ẹ̀ kọ́...- iléeṣẹ́ ológun kìlọ̀
- Àṣé àṣírí wà nínú Hijabu tí Aisha Yesufu ń wọ̀ lọ ìwọ́de












