2020 International day for Rural Women, Garri Ondo: Owó tà ń ná láti ṣe Garri tà kìí ṣe kékeré
Garri olóyọ̀ ti dé'lẹ̀! Wo iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ kó tó dé'lẹ̀.
Arabinrin Felicia to jẹ oniṣowo Garri ni agbègbè ilu Akure ṣalaye ilana ti wọn maa n tẹle lati yan ounjẹ ilẹ Naijiria yii, Garri.
- Ìyá gómìnà Seyi Makinde dágbére fáyé lẹ́ni ọdún 81
- Gbọ́ ìtàn bí ikọ̀ SARS ṣe dà bó ṣe dà láti ẹnu Ọ̀gá ọlọ́pàá tó dá SARS sílẹ̀
- Ìjọba kéde ọjọ́ ìwọlé àwọn àgùnbánirọ̀ sí ìpàgọ́ lẹ́yìn Covid 19- Sunday Dare
- #EndSARS: Àwọn olùwọ́de kọ etí ikún sí àṣẹ ijọba, wọ́n tẹ̀sìwájú ìwọ́de l'Abuja
- Kanye West, Ozil, Boyega, àti àwọn gbajúmọ̀ ilẹ̀ okèèrè tó ṣàtìlẹyìn fún ìpolongo #ENDSARS
"Owó tà ń ná láti ṣe Garri tà kìí ṣe kékeré". Felicia jẹ ko di mimọ wi pe ki wọn to lọ wu ẹgẹ ni oko, ki wọn to bẹẹ, ṣiṣan, lilọ, kiko, titẹ ri ati bẹẹ bẹẹ lọ plu imọtoto, kii ṣe ere ọmọde rara.
Bakan naa iye ọjọ ti wọn fi n ṣe Garri ko kere ṣugbọn ko le din ni ọjọ mẹfa rara.
- Àjọ elétò ìdìbò kéde ọjọ́ tí ìdìbò aàrẹ Nàìjíríà 2023 yóò wáyé
- Wo àwọn ojúṣe àti èèwọ̀ fún ikọ̀ ọlọ́pàá SWAT tó gba iṣẹ́ lọ́wọ́ SARS
- Pásítọ̀ Enoch Adeboye darapọ̀ mọ̀ #ENDSARS, ó fún ìjọba Nàìjíríà ní ìmọ̀ràn ọ̀nà àbáyọ
- Ijọba ipinlẹ Anambra pasẹ ma mu Gaari mọ
- 'Èèwọ̀' gààrí fún àwọn èèyàn ipínlẹ̀ Ondo
- Kíni ọ̀nà àbáyọ sí àìsàn Lassa Fever?
Iṣẹ Garri yiyan nilo agbara ati ọpọlọpọ iṣẹ gẹgẹ bi Felicia ati awọn akẹgbẹ rẹ to ku ṣe n ṣe e ni ibudo yii.
Sibẹ pẹlu gbogbo eleyii, awọn obinrin to n yan Garri ta yii ni owo ti wọn n na lati ṣe e gan pọ ṣugbọn ere to wa lori ni wọn fi n gbe ọpọlọpọ nkan ṣe ninu ile.


