Àṣà àti èdè Yorùbá dùn púpọ̀, o ní ìtumọ̀ kíkún
Ṣé iwọ ti ri iru ọmọ bẹẹ ri?
Idagbasoke ede ati aṣa Yoruba lo jẹ BBC Yoruba logun kaakiri agbaye.
Eyi lo mu wa jade lọ beere irufẹ ọmọ ti Yoruba n pe ni olugbodi.
- Ṣé àwọn ọmọ rẹ lè sọ Yorùbá tó àwọn ọmọ Amẹrika yìí?
- Owó oṣù 'Professor' ju ti 'Perm Sec' lọ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní 1963- Emeritus Ayo Bamgbose
- Wo bí arábìnrin yìí ṣé dáhùn sí ìbéèrè níbi ètò ìsìnkú ará rẹ̀
- Ọ̀wọ́ngógó ọjà ní Nàìjíríà gbéra dé ìdá 19.6%, wo ohun tó túmọ sí fáráàlú
- Tobi ní òun kò ní jẹ́ asáré ojú títì lásán, mo sì ń tì í lẹ́yìn - Alàgbà Amusan
Olugbodi jẹ ọkan alara orukọ Amutọrunwa ti iran Yoruba maa n sọ ọmọ wọn.
Yatọ si orukọ Abisọ, Inagijẹ, Adape, Ẹsin, Iṣẹ idile ati bẹẹ bẹẹ lọ, orukọ amutọrunwa ni a n sọ ọmọ nipasẹ bi a ṣe bii ati irufẹ ipo to fi wa saye.
- Bí ikú ilé kò bá pani...ìkìlọ̀ rèé fún ẹ̀yin ọmọ Yorùbá tí ẹ n gbàbọ̀dè f'ájínigbé- Oba Francis Alao
- Yuroopu ni wọ́n sọ pé à ń lọ ṣùgbọ́n Morocco ni mo ti bá ara mi nínú iṣẹ́ aṣẹ́wó- Abosede
- Wo àwọn nọ́mbà ìpè agbófinró tó yẹ kò mọ̀, èyí tó pè tí ìkọlù agbébọn bá dé
- Àwọn aya Yekeen Ajileye ló fa ìpinyà láàrin wa débi pé mo fẹ́ pa ara mi - Abija
- 'Láti ojú orun, ohùn kan máa ń tọ́ka ewé àti ègbòogi sí mi, báyìí la ṣe ń ṣe agbo fún ǹkan ọmọ ọkùnrin'
- Kíni ẹ mọ̀ nípa Ọmọ́táyọ̀ Olútóyè, Ọ̀jọ̀gbọ́n obìnrin àkọ́kọ́ nínú ẹkọ́ èdè Yorùbá lágbàyé
- Kìí ṣe gbájúẹ̀ nìkan lọmọ Nàìjá ń ṣe lókè òkun!
Iyalẹnu lo jẹ fun wa pé ọpọ ninu awọn ti a fi ọrọ wa lẹnu wo ko fi bẹẹ gba idahun iru ọmọ ti Olugbodi jẹ.
Ṣugbọn inu wa dun pe ibeere yii jẹ ki awọn eniyan gbero lati pada lọ sile lọ beere nipa olugbodi lọwọ awọn agbalagba ile wọn.
A n parọwa fun koowa lati fi ede Yoruba ati aṣa ọmọluwabi kọ ọmọ wa lati kekere.
- Èmí ò gbàgbọ́ pé iṣẹ́ kan wà tí ọkùnrin lè ṣe tí obìnrin kò lè ṣe- Obìnrin tó ń wa tírélà
- Egungun Oloolu ti ilẹ̀ Ibadan fojú han aráyé! Gbọ́ àwọn ǹkan tó ń dẹ́rù ba obìnrin, ọmọde nípa rẹ̀ àti èèwọ̀ rẹ̀
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- Ìdí réè tí àwọn ọmọ mi kò fi gbọdọ̀ pè mi ní Sanyeri-Olaniyi Afonja
- Ǹkan ti ọlọ́pàá sọ rèé lórí ìjà Fulani àti OPC tó mú ẹ̀mí èèyàn mẹ́rin lọ ní Kwara
Olugbodi ni ọmọ ti a bi to ni ika ọwọ mẹfa.
Ika ọwọ kẹfa yii ni awọn eeyan gba pe Ajé ni.
Ajé ni iranṣẹ owó. ọlà ati aṣeyọri ninu igbagbọ Yoruba.
Ọpọ igba ni ika kẹfa yii maa n ré danu bi ọmọ naa ba ṣe n dagba sii tabi ti wọn maa n gee kuro nile iwosan.
Igba miran awọn agba ile maa n so okun mọ ika rebete yii titi a si fi re sọnu.