Oba Francis Olusola Alao: Agbófinró, Fijilanté àti Amotekun ń gbìyànjú ṣùgbọ́n...
Ijọba Buhari, ǹkan ti bájẹ́, ẹ dìde ẹ tún ńkan ṣe nítorí orúkọ rere sàn ju wúra lọ- Oba Olugbon
Oba Francis Olusola alao to je Oba Olugbon nijoba ibile Suurulere ni Ogbomosho ni ipinle Oyo ni Iwo oorun guusu Naijiria gbalejo BBC Yoruba.
Kabiyesi salaye ni kikun ohun to sele nibi ijingbe ati ikolu to waye lona meta leralera ni Ogbomoso laipẹ.
- Peter Obi kò lè rí tó alátìlẹyìn igba ni ìpínlẹ̀ Kaduna- El-Rufai
- Dapo Abiodun faraya lẹ́yìn tí wọ́n ri Ireoluwa ti wọn jigbe l’Ogun
- Raila Odinga nìyí olùdíje ipò ààrẹ tó ti lulẹ̀ ní ìgbá márùn ún ọ̀tọ̀tọ̀ ní Kenya
- Mọ̀ síi nípa William Ruto, ààrẹ tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn ní Kenya
- Mo pàṣẹ̀ ètò aàbò tó gbóòrìn ní gbogbo iléẹ̀kọ́, iléèwòsàn lásìkò yìí- Alkali olórí ọlọ́pàá Nàìjíríà
Bakan naa lo tun kilo fun awọn ọmọ Yoruba to n gbabọde pẹlu ajeji lati mu wahala de ba awọn olugbe ilẹ Oodua.
O ni bi ko ba si ọwọ ọmọ onile ninu, o ṣoro fun ajoji lati mọ saare afọju.

Oríṣun àwòrán, @Presidency
Ni afikun, Oba Olugbọn tun sọ pe o ti hande pe ejo lọwọ ninu lori ọrọ ijinigbe bayii.
Kabiesi gba gbogbo iran Yoruba nimọran lati ji giri si eto aabo wa.Ìhá Buhari àtìjọba rẹ̀ sọ́rọ̀ ìjínigbé ń gbin ẹ̀rù sọ́kàn gbogbo ọmọ Nàìjíríà - Afenifere
Bakan naa lo gboriyin fun iko Amotekun, Fijilante ati awọn agbofinro pe won n sise, omi lo pọ ju ọka lọ.
O tun gab ijọba Buhari nimọran lati gbogun ti iwa igbesunmomi ati ijinigbe to n gbile sii bayii.
- APC ní ìpínlè Oyo ló ní pé àwọn kò fẹ́ Adelabu mọ́, yée parọ́ mọ́ APC mọ́- Morka
- Ọ̀wọ́ngógó ọjà ní Nàìjíríà gbéra dé ìdá 19.6%, wo ohun tó túmọ sí fáráàlú
- Nkan tí ọlọ́pàá sọ rèé nípa arákùnrin ''afurasí agbésùmọ̀mí '' tó múra bí obìnrin tí ọwọ́ bá lEko
- Ọkùnrin kàn pàdánù ẹ̀mi rẹ ní ilé itùrà lẹ́yìn tí ó pàdé olólùfẹ́ orí ayélujára-
- Wo bí àwàdà tí adẹ́rìnpòṣónú ṣe pé àwọn adigunjalé ń bọ̀ wá sí bánkì ṣé sọ adẹ́rinpòṣónú di èrò ẹ̀wọ̀n