Ekiti 2018: Àwọn àrímáleèlọ àwòrán láti ibi ìpolongo PDP l'Ékìtì

Ẹ wo aworan awọn to lorukọ ni ẹgbẹ oṣelu PDP bi wọn se peju-pesẹ sibi eto aṣekagba ipolongo PDP fun idibo gomina nilu Ado Ekiti;

gbagede ti ipolongo naa ti waye
Àkọlé àwòrán, Agogo meji abọ ọsan ni eto naa, to yẹ ko ti bẹrẹ ni agogo mẹwa, to bẹrẹ.
Atiku, Fayose atawọn adari PDP miran
Àkọlé àwòrán, Ọjọgbọn Olusola Kolapo Eleka ni oludije fun ẹgbẹ oṣelu PDP
9ice n kọrin
Àkọlé àwòrán, Gbogbo ayika ibudo ipolongo naa lo kun fun ero ti lilọ bibọ ọkọ si ti di iṣoro pẹlu.
Awọn eekan ẹgbẹ oselu PDP kan
Àkọlé àwòrán, Awọn to lorukọ lẹgbẹ oṣelu PDP ni wọn ti peju-pesẹ sibi eto aṣekagba ipolongo PDP fun idibo gomina nilu Adfo Ekiti
Alaga PDP ati olori awọn obinrin ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ekiti
Àkọlé àwòrán, Ilu Ado Ekiti ti n sọ̀kutu-wọ̀wọ̀ fun iwọde ita gbangba fun ipolongo ibo fun oludije fun ipo gomina ninu ẹgbẹ oselu PDP, Ọmọwe Kọlapọ Olusọla
Taye Currency, gbajugbaja olorin fuji
Àkọlé àwòrán, Awọn olorin pẹlu ko gbẹyin
Atiku, Fayose atawọn adari PDP miran
Àkọlé àwòrán, Ọjọgbọn Olusola Kolapo Eleka ni oludije fun ẹgbẹ oṣelu PDP
Awọn eekan ẹgbẹ oṣelu PDP
Àkọlé àwòrán, Igbakeji aarẹ orilẹede Naijiria nigbakanri, Atiku Abubakar lo lewaju awọn eekan ẹgbẹ oṣelu PDP de ibẹ
Egungun ni ibi ipolongo ibo
Àkọlé àwòrán, ' Ara ọrun' gan bawọn de ibẹ
Fayose
Àkọlé àwòrán, Aṣekagba ipolongo ibo naa waye ni agbegbe Ojumose roundabout ni ilu Ado-Ekiti
agbegbe Ojumose roundabout ni ilu Ado-Ekiti
Àkọlé àwòrán, Gbogbo awọn alatilẹyin ẹgbẹ oselu PDP nipinlẹ Ekiti ati yika ilẹ wa Naijiria lo wa nibẹ