Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ọba tó dá olóyé dọ̀bálẹ̀ níta gbangba nipinlẹ Ogun ma ti fojú ba iléẹjọ́ ọ,
ẹn ẹn,
Eyi waye lẹyin ti gomina ni ki kabiyesi naa lọ rọọkun nle foṣu mẹfa
Ileeṣẹ ọlọpaa ni idajọ ododo lawọn n beere lori ọrọ naa
Kan soju opo BBC.Com/Yoruba lati mọ bi igbejọ ṣe lọ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Eti to ba gbọ alọ
O yẹ ko gbọ abọ, ewo laa tun ri gbọ o
Ijọba apapọ lo ma sọ pe irọ to jina si otitọ ni iroyin kan to jade lana pe ijọba tun fẹ fowo kun owo ina mọnamọna
oludamọran Aarẹ lori eto amuṣagbara ni awọn akọroyin ṣi oun gbọ ni
Ẹkunrẹrẹ n bẹ lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Idi wo gan an ni iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC lori afikun tariifu ori ipe ati data ko fi waye mọ lonii?
Bẹẹ la a bi ni o, ohun ti aarẹ NLC sọ ni pe ijọba ti gbe igbimọ kan dide
lati ṣiṣẹ lori ọrọ naa fun ọsẹ meji
O ni lẹyin naa lẹgbẹ oṣiṣẹ yoo kede igbesẹ to kan
















