Owọ́ ọlọ̀pàá tẹ̀ àwọn awakọ̀ tó bẹ́ orí akẹgbẹ́ wọn fi se oògùn owó

Awon ọlọ̀paa ti kede pe awọn ti mu awọn afurasi méjì ti wọ́n lọ́wọ́ ninu iku akẹgbẹ́ wọn kan lẹ́nu isẹ́.

Samuel Amemasi ẹni ọdun mejilọ́gbọ̀n, ati Joseph Kwesi Mawuwone ẹni ọdun mẹ́talelogun

Ni owọ́ awọn agbofinro ti tẹ́ ni orile-ede Ghana.

Awọ́m mejeeji ni wọ́n ni wọ́n sekupa awako Taxi kan lati fi ori re soogun owo.

Awon alafojuri isẹ̀lẹ̀ naa salaye fun olopaa pe awọ́n afurasi yii n sare buruku ninu ọ́kọ́ ti wọ́n wa, wọ́n si kọ̀ lati duro nigab ti awọ́n olopaa da won duro fun ayewo.

Lasiko ti awọn afurasi yii n gbe ori awako naa lo ninu ọ̀kọ̀ ero won ni owo agbofinro tẹ́ wọ́n ni agbegbe Hobor ni ijoba ibile Ga South Municipality lale ojo Aiku to koja.

Lojiji ni oko won deede dojude nigba ti wọ̀n n sare lo ti awọn ara adugbo to sunmọ oko naa lati ran wọ́n lọ́wọ́ deede ri ori tutu ninu oko naa.

Nomba oko naa ni GW-5532-12

Leyin naa ni ọ̀kan ninu wọ́n sa lo.

Nkan ii eni ti won pa

Oríṣun àwòrán, @Seth Kofi Agyuei

Bawo ni oogun owo naa se sele?

Awon ara ilu so fun BBC pe ọ̀kan lara awọ́n afurasi naa lo fio enu ara rẹ́ ka leyin ti ọ́wọ́ tẹ́ wọn pe oogun owo ni awọn fe fi roi tutu naa se .

O ni pe awon daa bi ogbon ni ti awon si tan ‘ore won pe ko sin awon lo sibi inawo oku kan ki aown to pa a ti won si ge ori re.

O ni pe okun ni won fi fun awako naa lorun.

Ijamba oko to sele nigab ti olopaa da won duro lo tu gbogbo asiri.

Awon agbofinro ni pe won ti ko gbogbo won lo si ago won fun iwadii ti won si ti gbe ori naa lo si ile igbokusi ni Ghana.