Iran Arak Zoo: Kìnìún méjì ṣekúpa olùṣọ́gbà ẹranko ní Iran

kinihun

Oríṣun àwòrán, @others

Àkọlé àwòrán, Kinihun oloola iju kuro lẹran aa sin ninu ile

Kiniun meji fa oluṣogba ẹranko to n fun wọn ni ounjẹ ya pẹrẹpẹrẹ lorilẹ ede Iran.

Ọgba ẹranko Arak ni Iran iṣẹlẹ ọhun ti ṣẹlẹ ni Iran.

Awọn ti iṣẹlẹ naa ṣoju wọn sọ pe awọn kiniun meji naa sa kuro niluu ile wọn lẹyin ti wọn pa awọn to n tọju wọn tán.

-Kinni awọn oṣiṣẹ ọgbà ẹranko naa sọ?

Awọn oṣiṣẹ ọgbà ẹranko ọhun sọ pe awọn ọlọpaa at'awọn oṣiṣẹ ayika ti mu awọn kiniun ọhún pada sinu ile wọn.

Awọn ọlọpaa naa ri pe awọn kiniun ọhun ko fi ara ṣeṣe nigba ti wọn mu wọn.

Agbẹnusọ ọgbà ẹranko Arak ṣalaye pe ẹní ọdun mejidinlogoji ni ọkunrin to fẹ fawọn meji yii lounjẹ ki wọn to pa a.

Àkọlé fídíò, Alhaji Shanko

-Ọrọ awọn araalu lori iṣẹlẹ ọhun ree

Ohun ti a gbọ ni pe ọkunrin t'awọn kiniun pa yii lo wọ ile tọ awọn kiniun yii lọ ki wọn to.

Ọgba ẹranko Arak wa lara awọn ọgbà ẹranko tó tobi julọ lorilẹ ede Iran.

Àkọlé fídíò, Timothy Adegoke

A gbọ wi pe ọtalenirinwo eranko to jẹ orisii mẹrindinlaadọta to wa ni gbogbo orilede naa

Igala, agbo, kiniun wa lara awọn eranko

To wa ninu ọgbà ẹranko maa