Ekiti parades thugs: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ekiti sàfihàn àwọn òníjàgídíjàgán méjìdínlọ́gọ́rùn ún lónìí ní Ado Ekiti

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ekiti sàfihàn àwọn òní jàgídíjàgán méjì dín lọ́gọ́rùn ún lónìí ní Ado Ekiti
Awon ti won fura si bi Onijaduku, ti won je mejidinlọgọrun-un eniyan, ti wọn ti mu ni ibudo Ayẹwo ti awọn Ọmọ ologun ti o wa ni agbegbe Itawure, Efon Alaaye, laipẹ yii, ti fa le ọlọpaa lọwọ.
- Osun la fẹ́ kí ìgbẹ́jọ́ ikú Timothy Adegoke ti wáyé, kìí ṣe Abuja - Mọ̀lẹ́bí yarí
- Deji Akure tó lu aya rẹ̀ lójú títì, tí wọn rọ̀ lóyé, ti jáde láyé
- Èèyàn méjì dèrò ọ̀run nínú ìkọlù ọlọ́pàá àtàwọn afurasí akẹ́kọ̀ọ́ ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn Kwara Poly
- Òkú kú ní ẹ̀ẹ̀kejì nígbà tí òkú 400 jóná ráúráú ní mọ́ṣúárì, ẹbí bú sẹ́kún lẹ́ẹ̀kejì
- Àwọn ọmọbìnrin oníwọ́kuwọ́ ló mú kí ń yẹ̀bá nídìí iṣẹ́ tíátà
- Bí ayẹyẹ ìsìnkú Alao Akala yóò ṣe lọ rèé
- Àwùjọ àgbáyé, ẹ ṣèrànwọ́ fún Burkina Faso kó le borí ìṣòro - Olórí ìjọba ológun
Kini o ti koko sele seyin?
Ẹ rántí pé lọ́jọ́ tí ètò ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ku wakati diẹ, àwọn ọmọ ologun ní ojú ọ̀nà àyẹ̀wò Itawure mú àwọn tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ Onijaduku pẹ̀lú àwọn ìbọn ilewo, orísirísi ogun àti Ada.

Alukoro ileese olopaa, ASP Sunday Abutu, Nigba to n fi awon afurasi naa han, so pe iwadii ti pari ati pe won yoo fi oju ba ile ejo fun kiko ohun ija oloro kakiri ni ona àìtó.
Abutu so pe iwadi nlo lowo lori ẹni ti o pe awọn onijagidijagan wa si Ipinle Ekiti lati fa wahala.
Abutu gbóríyìn fún àwọn ọmọ ogun náà fún ìṣọ́ra wọn àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ileese ọlọpaa láti gbógun ti ìwà ọ̀daràn ní ìpínlẹ̀ náà.
Ni ipari, Abutu ni pe die lo ku ki owó awon agbofinro te awon to wa leyin awon janduku yii to n ti won leyin.
O ni laipe ni won maa mo eni to ko won wolu lati wa da wahala sile.

Bakan naa lo tun ki awon agbfinro ku ise takuntakun ti won n se lati daabo bo awon eniyan ipinle Ekiti.













