Kòkòrò oyin lé ọ̀pọ̀ èèyàn kúrò nílé l'órílẹ̀-èdè Cameroon

Oríṣun àwòrán, @BBOWT
Inu ibẹru ni awọn eeyan to n gbe ni awọn agbegbe kan nilu Maroua, lorilẹ-ede Cameroon wa bayii, nitori bi kokoro oyin ṣe yabo wọn.
Eeyan marun-un, ninu eyi ti ọmọde mẹrin wa, lo ti di eero ileewosan nitori iṣẹlẹ naa.
Eyi si ti mu ki awọn alasẹ o gba awọn araalu ni imọran láti fi ile wọn silẹ, titi ti wahala naa yoo fi wa sopin.
- Wo iye ìgbà mẹ́rin tí ìtàkùn ìpínná ní Nàìjíríà ti dákú lọ́dún 2020 nìkan
- Olorì Aláàfín tẹ́lẹ̀, Anuoluwapo Adeyemi gba àmì ẹ̀yẹ lórí ipa tó kó nínú oge ṣíṣe
- Gbajugbaja òṣèré ''Toromagbe'' nínú fíìmù ''Arelu'' ti jáde láyé
- Mi ò ṣe ẹ̀tánú Ọọ̀ni ilé Ifẹ̀, ọmọ ìyá mi ni ṣùgbọ́n...-Olugbo Obateru Akinruntan
Yatọ si eyi, àwọn oṣiṣẹ pana-pana ti wa ni ilu naa lati koju awọn kokoro ọhun.
Ohun to jẹ iyalẹnu fun awọn araalu naa ni pe ko si ẹni to mọ ibi ti awọn kokoro oyin ọhun ti wa.

Oríṣun àwòrán, @Planet_Bee
Saaju asiko yii, aṣọ ekisa ni awọn eeyan naa ma n dana sun lati le awọn kokoro ọhun.
- Wọ́n fẹ́ ba dáadáa ààrẹ Buhari jẹ́ ni wọ́n ṣe ń lọ́ kíkojú ìṣòro àbò mọ́ ikú àwọn àgbẹ̀ Koshebe
- Ẹ wo ọmọ Yoruba, Adewale Adeyemo tí yóò jẹ igbákejì akọ̀wé akápò ní ilẹ̀ Amẹrika
- Iyè àwọn àgbẹ̀ tí Boko haram dúmbú ní Borno ju ohun tẹ́ẹ gbọ́ lọ - UN
- Ṣe lóòtọ́ ní ọmọ Nàíjíríà mílíọ́nù 25 yóò má ló ìná Solar látí Dec 1, 2020?
Wọn ma n se eyi nitori pe eefin ati ooru ina ma n le àwon kokoro oyin kuro nibi ti wọn ba wa.
Sugbọn ṣa, igbesẹ naa ko sisẹ ni asiko yii nitori pe awọn oyin naa ko duro si oju kan.
Idi si niyii ti wọn fi ránṣẹ si awọn oṣiṣẹ pana-pana lati koju wọn.
- Ẹ wo ìdí tí Oby Ezekwesili ṣe ń pè fún àyẹ̀wò ọpọlọ fún Ààrẹ Buhari
- Bí mo bá leè rí ọmọ alágbe t'áyé fẹnu sí pé mo fi ẹlẹ́rìndòdò lá lójú, máa kúnlẹ bẹ ẹ - Motara
- Níbo ni Ọ̀gbẹ́ni 'Emma', tíṣà tí wọ́n ní ó lu ọmọ pa ní Ikorodu wà bayìí?
- N81m pọ̀ lóòtọ́ láti fi gé koríko Stadium, Ọ̀gá Mínísítà,èló lẹẹ́ san fáwa ọ̀dọ́ láti gè e?













