Haàà! N81m pọ̀ lóòtọ́ láti fi gé koríko Stadium, Ọ̀gá Mínísítà,èló lẹẹ́ san fáwa ọ̀dọ́ láti gè e?

Oríṣun àwòrán, SundayDareSD
Awuyewuye iye owo ti wọn yoo fi ge koriko ayika papa isere nla Naijria, Moshood Abiola Stadium lAbuja ti gbọna mi yọ.
Saaju ni Minisita feto idaraya ati ọrọ ọdọ ni Naijiria Sunday Dare ti tako iroyin kan ti ileeṣe iroyin Daily Trust gbe jade pe oun fẹ fi miliọnu mọkanlelọgọrin ge koriko Stadium naa.
Loju opo rẹ ni Twitter Sunday Dare ni irọ ati aṣikọ ọrọ toun sọ ninu ifọrọwanilẹnuwo ni nkan ti Daily Trust ṣe.

Oríṣun àwòrán, SundayDareSD
O ni ileeṣẹ eto idaraya ko gba iye yi ti ileeṣẹ to n mojuto ayika ni Abuja,AEPB, gbe wa pe awọn fẹ fi ge koriko ayika papa iṣere nla naa.
Ọgbẹni Sunday ni ati pe bawọn ba sọ fawọn ọmọ Naijiria pe miliọnu mọkanlelọgọrin lawọn fẹ fi ge koriko, ariwo yoo gbode.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Amọ ṣa bayi ti o ti ni awọn ko le san aduru owo yi lati fi ge koriko, awọn ọdọ Naijiria kan ti n beere lọwọ rẹ pe elo lo lẹ san jalẹ fawọn lati ṣe iṣẹ naa.
Ibeere wọn yi ta ri ka labẹ ọrọ Minisita to sọ soju opo Twitter ṣafihan bi awọn ọdọ ko ti se kọ lati ṣe iṣẹ kankan lopin igba to ba ti mu owo wa.
Gbogbo ẹyin ti ẹ ge koriko nileewe, ẹ sunmọ bi, iṣẹ ya!
Bawọn kan ṣe n bẹnu atẹ lu bi ileeṣẹ iroyin yi ti ṣ sọ nkan ti mInisista ko sọ lawọn mii n mu imọran wa lọna ati ge koriko papa iṣere nla Naijiria.
Esi awọn eeyan pe orisirisi pẹlu aba iye owo iṣẹ agbaṣẹ to yatọ si eyi ti AEPB lawọn fẹ gba fi ge koriko.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2
Mo kawe gboye PhD ninu koriko gigẹ ẹ gbe iṣẹ yi fun mi
Samuel A farabalẹ kọ lẹta si Minisita Dare Sunday ni pe ọjọ meji pere loun yoo fi ge gbogbo koriko ayika papa iṣẹrẹ naa tan.
Ko kọ lati gba N81million amọ ohun to ni oun yoo ṣe yatọ ni pe ọjọ meji lawọn yoo fi ṣe iṣẹ naa tan.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 3
Ohun tawọn miran naa sọ re nipa gbigba iṣẹ agbaṣe koriko gige ni papa iṣẹre Moshood Abiola ni Abuja.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 4

End of X post, 5

End of X post, 6