Justice Mustapha Akanbi f'ayé sílẹ̀ lẹ́ni ọdún 85

Adájọ́ Àgbà Mustapha Akanbi

Oríṣun àwòrán, Abdul Momoh

Àkọlé àwòrán, Justice Mustapha Akanbi f'ayé sílẹ̀

Adájọ́ Àgbà Mustapha Akanbi ti re 'bi àgbà ń rè. Òsìsẹ́fẹ̀yìntì ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn tó tún jẹ́ alága àkọ́kọ́ àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá ICPC papòdà ní àfẹ̀mójúmọ́ òní, ọjọ́ àìkú, ọjọ́ kẹta osù kẹ́fà ọdún 2018 lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́.

Olóògbé Wàkílì ti ilú Ilọrin f'ayé sílẹ̀ ní ẹni ọdún márùndínláàdọ́rin.

Ìsìnkú yóò wáyé lọsan ọjọ́ àìkú.

Àwọn abáni kẹdun sí ti n ṣe àbẹwò sí ilé olóògbé náà ni ìlú Ilorin.

Wọnyi ni akojopo àwòrán bi ètò ṣe n ló níbẹ.

Aworan isinku Mustapha Akanbi

Oríṣun àwòrán, Abdul Momoh

Àkọlé àwòrán, Adari Ajọ to n risi eto idanwo aṣewọle s'ile ẹkọ giga, JAMB Ojogbon Oloyede ati agba oje agbejoro Olaolu Alli
Isinku Adajo Mustapha Akanbi

Oríṣun àwòrán, Abdul Momoh

Àkọlé àwòrán, Won gbe iwe ibanikedun kale ti awọn eeyan si n fọwọ si
Aworan Abanikedun ni ile adajo Mustapha

Oríṣun àwòrán, Abdul Momoh

Àkọlé àwòrán, Ọpọ eniyan lo'n jaran Ologbee Akanbi

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, Ìṣẹlẹ iyinbon APC Ekiti : Ki gaan lo ṣẹlẹ?