Bed bugs: Wo ọ̀nà mẹ́fà tí o fi lè gbógun ti ìdun nínú ilé rẹ

Oríṣun àwòrán, Others
Kokoro idun le jẹ ki ile aye su eeyan ti wọn ba fi ibugbe ẹni se ibujoko.
Awọn idun wọnyii kii fo, amọ wọn le rin kiakia lori ilẹ, ogiri ati aja tabi orule.
Igba ojo ati otutu ti oju ọjọ ko dan mọnran ni kokoro bii idun ati aayan ma n ja julọ, paapaa ni Naijiria.
Ti a ko ba si kiyesara, awọn idun wọnyii le ba awọn eroja ti eniyan ba ko si inu ile jẹ.
- Ohun márùn ún tí ejò ń jẹ
- Ìgbà méje ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí ikọlu wáyé láwọn ọgbà ẹwọn Nàìjíríà
- "Ó yẹ kí ìjọba máa fún wa ní ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ tí oyún bá bàjẹ́ mọ́ wa lára"
- Àrà kengé! Alábòyun ṣe iṣẹ́ abẹ pẹ̀lú abẹfẹ́lẹ́, ó gbé ọmọ jádé nínú ara a rẹ̀
- Ẹ wo àwọn adarí ìjọ ní Naijiria tó tako abẹ́rẹ́ àjẹ́sára Covid-19 àti àwọn tó faramọ
- Genevieve ṣàlàyé ànfààní tó wà nínú ìbásùn òwúrọ̀ kùtù fáwọn lọ́kọ láya
Amọ ọna abayọ wa lati gbogun ti kokoro yii, nitori o le fa aisan iba, ki ara ma a dun eniyan, bẹẹ si ni nitori o maa n fa ẹjẹ eniyan mu ni.
Awọn idun wọnyii kii fo, amọ wọn le rin kiakia lori ilẹ, ogiri ati aja tabi orule.
Ona lati gbogun ti idun ninu ile re e;
Lilo Alubosa:
Idun korira oorun alubosa ninu ile to fi mo eku naa.
Ohun ti ẹ le ṣe ni pe ki e fi alubosa si awọn oriko inu ile, nibi ti wọn yoo ti ma a gbọ orun rẹ.
Amọ, ti alubosa naa ba ti bajẹ ko ni agbara mọ, nitori naa ẹ ma a jẹ ki alubosa to ba ṣi dara wa ninu ile ni igba gbogbo.
- Ẹ wo àwọn adarí ìjọ ní Naijiria tó tako abẹ́rẹ́ àjẹ́sára Covid-19 àti àwọn tó faramọ
- Kokoko lara mí le, Mo kàn ń gba ìtọ́jú ni London ni- Tinubu
- Ṣé ẹ ti rí 'Penis Fish,' ẹ̀ja tuntun tó rí bí nǹkan ọmọkùnrin tó lúwẹ̀ẹ́ jáde nínú òkun rí?
- Mínísítà Sunday Dare gbéná w'ojú Obasanjọ tó ní Buhari ò pèsè iṣẹ́ f'áwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà
- Ọlọ́pàá tají padà lẹ́yìn 'Coma' oṣù mẹ́sàán, 'sack letter' làwọn ọ̀gá rẹ̀ fi kíi káàbọ̀
- Ọwọ́ tẹ bàbá ẹni ọdún 52 tó ń bá ọmọ rẹ̀ lòpọ̀ fún ọdún méjì
Lilo Atarodo:
Ọna kan re e lati gbogun ti idun lai na owo pupo. Ẹ le fin ata wẹwẹ kaakiri inu ile paapaa ẹnu ọna ati awọn kọrọ ile.
Lilo Alubosa Ayu (Garlic):
Idun korira oorun Ayu ti ọpọ n pe ni garlic.
Ohun ti a le ṣe ni lati da garlic pọ mọ omi, lẹyin ti a ba ti ge galiiki naa si wẹwẹ, ki a fọn ọn si ẹnu ọna ile tabi awọn kọrọ yara.
Lilo Potato;
Ti a ba lọ potato ti a wọn si inu ile, idun tabi eku to ba jẹ ẹ, ikun rẹ yoo wu.
Koda, idun tabi eku tabi ọmọ onile naa yoo si ma a wa omi kiri, were to ba ti mu omi bayii, ni yoo gbẹmi mi.
- Eré ìfẹ́ di eré ẹkún! Olólùfẹ́ méjì lẹ̀pọ̀ lásìkò tí wọ́n n bá ara wọn sùn nínú adágún odò
- Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Ogun ti pàsẹ pé ki adarí OPIC tẹ́lẹ̀ri dá #40 miliọ̀nù padà
- Mínísítà Sunday Dare gbéná w'ojú Obasanjọ tó ní Buhari ò pèsè iṣẹ́ f'áwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà
- 'Àwa akẹ́ẹ̀kọ́ tako bí àwọn adarí fásitì OAU ṣe ti iléẹ̀kọ́, ìfẹ̀hónúhàn tẹ̀síwújú lórí ikú akẹgbẹ́ wa'
- Àwọn ọmọ Nàìjíría fẹ́ òfin Islam ju ìjọba awarawa lọ - El-Zakzaky
- "Ó yẹ kí ìjọba máa fún wa ní ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ tí oyún bá bàjẹ́ mọ́ wa lára"
Lilo Omi, Dettol ati Ọṣẹ:
Ẹ tun le gbogun ti idun nipa lilo omi ti ẹ ti po pọ mọ dettol pẹlu ọṣẹ.
E o wa fin in si gbogbo ile.
Idun nikan ko ni yoo pa, pẹlu aayan ati awọn kokoro miran.
Lilo Iyọ, Kerosiini àti Ọṣẹ ifọṣọ:
Ti o ba da iyo sinu kerosene ki o si po ọṣẹ ifọṣọ papọ mọọ.
Pelu omi diẹ ni yoo fi po papọ daadaa.
Wa a fọn ọn ka si ara gbogbo nkan ibusun ati aga tai awọn ibi ti idun naa le sa pamọ si ninu ile rẹ.
Oorun yii yoo pa awọn idun naa pẹlu ẹyin wọn.
Nibayii, o ti fihan gbangba pe idun korira ohun to ba ni oorun to lagbara, nitori naa a le gbogun ti wọn nipa lilo awọn ohun eroja ti a ti kọ silẹ yii ninu ile.
Ni ipari ki o sa gbogbo nkan eelo onigi ati bẹẹdi ti o fi n sun pẹlu awọn aga rẹ sinu oorun ọsan gangan pẹlu


















