Ohun márùn ún tí ejò ń jẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ejo jẹ ẹranko to maa n faya wọ, lati ẹka ẹranko to maa n jẹran nikan, ti o si le jẹ ajo bi ara rẹ.
Lara awọn ejo yi a maa dẹkun fun ẹran ti wọn ba fe paa jẹ, ti awọn ejo miran si ma a n wa ounjẹ jijẹ wọn lọ.
Ejo ma a n mi ounjẹ wọn ni nitori wọn ko ni eyin ti wọn ma fi jẹ ounjẹ wọn.

Ohun marun un ti ejo n jẹ ni:
- Ẹyin adiyẹ
- Kokoro
- Ẹlẹdẹ
- Ẹja
- Owo ti o to miliọnu mẹrindinlogoji naira?

Awọn nnkan miran wo ni o lero wi pe ejo le jẹ?
Kan si wa lori opo ikan ayelujara wa to fi mọ Facebook ati Instagram lori opo bbc.com/yoruba.













